Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 302 Iwo Isun imole Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 302 Iwo Isun imole Lyrics

Hymn 302 Iwo Isun imole Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 302 Iwo Isun imole Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

APA I

1 Iwo Isun imole;
Ogo ti ko l’ okunkun;
Aiyeraiye, titi lai,
Baba Mimo, gbo ti wa.

2 Kanga Iye tin san lai;
Iye ti ko l’ abawon,
Iye t’ o ni irora,
Baba Mimo, gbo ti wa.

3 Olubukun, Olufe,
Omo Re mbe O loke;
Emi Re nrado bo wa;
Baba Mimo, gbo ti wa.

4 Y’ ite safire Re ka
L’ osumare ogo ntan;
O kun fun Alafia,
Baba Mimo, gbo ti wa.

5 N’ iwaju ’te anu Re
L’ awon Angeli npade,
Sugbon wow a lese Re,
Baba Mimo, gbo ti wa.

6 Iwo ti okan Re nyo
S’ amusua t’ o pada,
T’O mo ’rin re lokere,
Baba Mimo, gbo ti wa.

7 Okan ti nwa isimi;
Okan t’ eru ese npa;
B’ om’- owo ti nke f’ omu,
Baba Mimo, gbo ti wa.

8 Gbogbo wa ni alaini
L’ ebi, l’ ongbe at’ are;
Ko si ede f’ aini wa,
Baba Mimo, gbo ti wa.

9 Isura opolopo
Ko l’O kojo bi Oba?
Ainiye, aidiyele?
Baba Mimo, gbo ti wa.

10 ’Wo ko da Omo Re si,
Omo Re kansoso na,
Tit’ O fi par’ ise Re,
Baba Mimo, gbo ti wa.

APA II

1 ’Wo t’O sunmo, gb’ O nkedun,
T’O gbo ’gbe Re ikehin;
T’O jowo Re lati ku.
Baba Mimo, gbo ti wa.

2 Iwo ti o le gba ni
L’owo iji iparun,
L’owo ’boji at’ iku.
Baba Mimo, gbo ti wa.

3 ’Wo low’ otun Eniti
On joko nisisiyi,
T’O gunwa bi t’ isaju
Baba Mimo, gbo ti wa.

4 ’Wo t’O f’ ore de l’ade,
T’O si gbe mo aiya Re,
On n’ Imole oju Re.
Baba Mimo, gbo ti wa.

5 Gbogb’ ebun meje orun,
Lodo Emi meje ni
A fi won fun l’ ainiwon
Baba Mimo, gbo ti wa.

6 L’ase Re ni Emi wa,
’Mole at’ ela ahon,
L’oko Olurapada.
Baba Mimo, gbo ti wa.

7 Fun wa li akoko yi,
Lat’ inu ebun Re wa,
’Mole, iye, agbara.
Baba Mimo, gbo ti wa.

8 Gbo ’gbe wa, gbo aini wa;
Gbo, Emi mbebe n’nu wa:
Gbo, tori Jesu nsipe.
Baba Mimo, gbo ti wa. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 301 Oju kan mbe ti ki togbe Lyrics
Next: Hymn 303 Aigbagbo, bila ! temi l’ Oluwa Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 449 Balogun! Olugbala wa Lyrics
  • Hymn 394 Jesu, mase je k’a simi Lyrics
  • Hymn 573 Baba wa, Olodumare Lyrics
  • Hymn 57 Wo oju sanma ohun ni Lyrics
  • Hymn 125 Ma sise lo, mase sare Lyrics
  • Hymn 463 Jesu onirele Lyrics
  • Hymn 487 Ile- eko ojo ’simi Lyrics
  • Hymn 455 Baba, Apat’ agbara wa Lyrics
  • Hymn 470 Gba Jesu wo tempili lo Lyrics
  • Hymn 72 Onidajo mbo wa Lyrics
  • Hymn 280 Mimo, mimo, mimo! Olodumare! Lyrics
  • Hymn 277 Emi orun, gb’ adura wa Lyrics
  • Hymn 233 Mo wi fun olukuluku Lyrics
  • Hymn 358 Nihin mo j’ alejo Lyrics
  • Hymn 4 Oluwa mi, mo njade lo Lyrics
  • Hymn 109 Jesu, b’ ise tab’ iya ni Lyrics
  • Hymn 397 Olorun ogbon at’ ore Lyrics
  • Hymn 55 Oluwa mbo; aiye o mi Lyrics
  • Hymn 446 Eyi l’ ase nla Jehofa Lyrics
  • Hymn 375 Ha! Egbe mi, e w’ asia Lyrics
  • Hymn 392 Tan ‘mole Re si wa Lyrics
  • Hymn 176 Elese, e yipada Lyrics
  • Hymn 357 Kristian, ma ti ’wa ’simi Lyrics
  • Hymn 60 ’Mole t’o da gbogbo nkan Lyrics
  • Hymn 214 Leba iboji Jesu mi Lyrics
  • Hymn 229 Jesu t’o ku, k’ o gb’ aiye la Lyrics
  • Hymn 35 Akoko odun at’ osu Lyrics
  • Hymn 399 E wa s’apakan, k’e simi die Lyrics
  • Hymn 595 F’ awon Ijo ti nsimi Lyrics
  • Hymn 356 Jesu npe wa, losan, lorun Lyrics
  • Hymn 131 Iwo ti okunkun Lyrics
  • Hymn 110 Enyin enia Olorun Lyrics
  • Hymn 371 Jesu mimo, Ore airi Lyrics
  • Hymn 495 A o pade leti odo Lyrics
  • Hymn 256 Ile ayo kan wa Lyrics
  • Hymn 556 Fun anu to po b’iyanrin Lyrics
  • Hymn 297 Tori Mi at’ Ihinrere Lyrics
  • Hymn 262 Oru ko si l’orun Lyrics
  • Hymn 516 Igba asale ti dun to Lyrics
  • Hymn 518 Lala alagbase tan Lyrics
  • Hymn 17 L’ oju ale, ’gbat ’orun wo Lyrics
  • Hymn 486 Oj’ oni lo Lyrics
  • Hymn 138 ’Ranse Olorun, e ma kede Re Lyrics
  • Hymn 249 Ile ewa wonni, b’ o ti dara to Lyrics
  • Hymn 244 Olorun goke lo Lyrics
  • Hymn 420 Olori Ijo t’ orun Lyrics
  • Hymn 289 Bibeli mimo t’ orun Lyrics
  • Hymn 522 Itanna t’o bo ’gbe l’ aso Lyrics
  • Hymn 581 Awa fe ohun aiye yi Lyrics
  • Hymn 355 Iwo l’ Ona; – odo Re ni Lyrics
  • Hymn 70 Wo ! Oluwa l’ awosanma Lyrics
  • Hymn 259 Lai lodo Oluwa Lyrics
  • Hymn 201 Oke kan mbe jina rere Lyrics
  • Hymn 135 Gbo iro efufu, lat’ ona jijin Lyrics
  • Hymn 98 Olorun Betel, eniti Lyrics
  • Hymn 99 Oluwa alafia wa Lyrics
  • Hymn 411 Wa sodo mi, alare Lyrics
  • Hymn 213 N’ iwaiya ’jakadi, On nikan nja Lyrics
  • Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics
  • Hymn 202 Okun l’ ale, tutu n’ ile Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version