Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 302 Iwo Isun imole Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 302 Iwo Isun imole Lyrics

Hymn 302 Iwo Isun imole Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 302 Iwo Isun imole Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

APA I

1 Iwo Isun imole;
Ogo ti ko l’ okunkun;
Aiyeraiye, titi lai,
Baba Mimo, gbo ti wa.

2 Kanga Iye tin san lai;
Iye ti ko l’ abawon,
Iye t’ o ni irora,
Baba Mimo, gbo ti wa.

3 Olubukun, Olufe,
Omo Re mbe O loke;
Emi Re nrado bo wa;
Baba Mimo, gbo ti wa.

4 Y’ ite safire Re ka
L’ osumare ogo ntan;
O kun fun Alafia,
Baba Mimo, gbo ti wa.

5 N’ iwaju ’te anu Re
L’ awon Angeli npade,
Sugbon wow a lese Re,
Baba Mimo, gbo ti wa.

6 Iwo ti okan Re nyo
S’ amusua t’ o pada,
T’O mo ’rin re lokere,
Baba Mimo, gbo ti wa.

7 Okan ti nwa isimi;
Okan t’ eru ese npa;
B’ om’- owo ti nke f’ omu,
Baba Mimo, gbo ti wa.

8 Gbogbo wa ni alaini
L’ ebi, l’ ongbe at’ are;
Ko si ede f’ aini wa,
Baba Mimo, gbo ti wa.

9 Isura opolopo
Ko l’O kojo bi Oba?
Ainiye, aidiyele?
Baba Mimo, gbo ti wa.

10 ’Wo ko da Omo Re si,
Omo Re kansoso na,
Tit’ O fi par’ ise Re,
Baba Mimo, gbo ti wa.

APA II

1 ’Wo t’O sunmo, gb’ O nkedun,
T’O gbo ’gbe Re ikehin;
T’O jowo Re lati ku.
Baba Mimo, gbo ti wa.

2 Iwo ti o le gba ni
L’owo iji iparun,
L’owo ’boji at’ iku.
Baba Mimo, gbo ti wa.

3 ’Wo low’ otun Eniti
On joko nisisiyi,
T’O gunwa bi t’ isaju
Baba Mimo, gbo ti wa.

4 ’Wo t’O f’ ore de l’ade,
T’O si gbe mo aiya Re,
On n’ Imole oju Re.
Baba Mimo, gbo ti wa.

5 Gbogb’ ebun meje orun,
Lodo Emi meje ni
A fi won fun l’ ainiwon
Baba Mimo, gbo ti wa.

6 L’ase Re ni Emi wa,
’Mole at’ ela ahon,
L’oko Olurapada.
Baba Mimo, gbo ti wa.

7 Fun wa li akoko yi,
Lat’ inu ebun Re wa,
’Mole, iye, agbara.
Baba Mimo, gbo ti wa.

8 Gbo ’gbe wa, gbo aini wa;
Gbo, Emi mbebe n’nu wa:
Gbo, tori Jesu nsipe.
Baba Mimo, gbo ti wa. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 301 Oju kan mbe ti ki togbe Lyrics
Next: Hymn 303 Aigbagbo, bila ! temi l’ Oluwa Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 127 Sin awon onse Re, sin won Lyrics
  • Hymn 575 A fi ipile yi le’ le Lyrics
  • Hymn 485 Nihin l’ awa nje ’rora Lyrics
  • Hymn 456 Jesu, Baba omode Lyrics
  • Hymn 96 Baba ki m’ ya odun yi Lyrics
  • Hymn 378 Omogun Krist, dide Lyrics
  • Hymn 14 Ife Re da wa si loni Lyrics
  • Hymn 89 Igba mi mbe li owo Re Lyrics
  • Hymn 597 Iyin, ola, ogo, ’bukun Lyrics
  • Hymn 373 Didan l’ opagun wa Lyrics
  • Hymn 584 Enit’ O la ’ju afoju Lyrics
  • Hymn 76 E ji enyin enia Lyrics
  • Hymn 394 Jesu, mase je k’a simi Lyrics
  • Hymn 253 Jerusalem ibi ayo Lyrics
  • Hymn 31 Bi mo ti yo, lati gb’ oro Lyrics
  • Hymn 574 Oro alafia Lyrics
  • Hymn 352 Ewa ’tanna oro kutu Lyrics
  • Hymn 6 Krist, Ologo, Olola Lyrics
  • Hymn 143 Oluwa, ma moju kuro Lyrics
  • Hymn 223 “Kabo, ojo rere,” l’ao ma wi titi Lyrics
  • Hymn 425 E wa k’ a da orin wa po Lyrics
  • Hymn 437 Jesu, ‘Wo oninure Lyrics
  • Hymn 141 Jesu, l’ojo anu yi Lyrics
  • Hymn 248 O ti lo. Awosanma Lyrics
  • Hymn 573 Baba wa, Olodumare Lyrics
  • Hymn 363 Olorun emi wa, at’ igbala wa Lyrics
  • Hymn 176 Elese, e yipada Lyrics
  • Hymn 491 Mase huwa ese Lyrics
  • Hymn 408 Yara, elese k’ o gbon Lyrics
  • Hymn 153 Ko to k’ awon mimo beru Lyrics
  • Hymn 13 Orun fere wo na Lyrics
  • Hymn 184 Jesu, l’ara Re l’awa nwo Lyrics
  • Hymn 431 Jesu ayo okan gbogbo Lyrics
  • Hymn 63 L’ eba odo Jordani ni Lyrics
  • Hymn 496 Oluwa, k’ a ha w’ odo Re Lyrics
  • Hymn 564 L’oko Jesu, gbogbo ekun yio wole Lyrics
  • Hymn 290 Bawo ni awon ewe wa Lyrics
  • Hymn 287 Olorun Olodumare Lyrics
  • Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics
  • Hymn 34 Eyi l’ ojo t’ Oluwa da Lyrics
  • Hymn 28 A be, a fe ri O Lyrics
  • Hymn 55 Oluwa mbo; aiye o mi Lyrics
  • Hymn 487 Ile- eko ojo ’simi Lyrics
  • Hymn 215 Isimi awon mimo Lyrics
  • Hymn 459 Ojo oni lo tan Lyrics
  • Hymn 474 Olorun, ran imole Re Lyrics
  • Hymn 146 Jesu, agbara mi Lyrics
  • Hymn 586 Ma koja mi, Olugbala Lyrics
  • Hymn 12 A gboju soke si O Lyrics
  • Hymn 462 Oluso- agutan l’ Olugbala wa Lyrics
  • Hymn 297 Tori Mi at’ Ihinrere Lyrics
  • Hymn 397 Olorun ogbon at’ ore Lyrics
  • Hymn 68 Oluwa ni Oba Lyrics
  • Hymn 257 Oke kan mbe t’ o ga Lyrics
  • Hymn 548 Olugbala, a tun fe f’ohun kan Lyrics
  • Hymn 428 Ohun t’a fi fun O Lyrics
  • Hymn 515 A! nwon ti gun s’ ebute Lyrics
  • Hymn 353 Jesu, mo gb’ agbelebu mi Lyrics
  • Hymn 448 Nihinyi n’ isimi gbe wa Lyrics
  • Hymn 128 Eni t’ o joko low’ otun Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version