Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics

Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Tal’ awon wonyi b’ irawo,
Niwaju ite mimo,
Ti nwon si de ade wura,
Egbe ogo wo l’eyi?
Gbo! nwon nko Alleluya,
Orin iyin Oba won!

2 Tali awon ti nko mana,
T’ a wo l’ aso ododo?
Awon ti aso funfun won
Y’o ma funfun titi lai,
Beni ki y’o gbo lailai:
Nibo l’ egbe yi ti wa?

3 Awon wonyi l’ o ti jagun,
F’ ola Olugbala won;
Nwon jijakadi tit’ iku,
Nwon ki b’ elese kegbe:
Wonyi ni ko sa f’ ogun,
Nwon segun nipa Kristi.

4 Wonyi l’ okan won ti gbogbe,
Ninu danwo kikoro;
Wonyi li o ti f’ adura,
Mu Olorun gbo tiwon;
Nisisiyi nwon segun,
Olorun re won l’ekun.

5 Awon wonyi l’ o ti sora,
Ti nwon fi ife won fun Kristi;
Nwon si y’ ara won si mimo,
Lati sin nigbagbogbo;
Nisisiyi li orun,
Nwon wa l’ ayo l’ odo Re. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 414 F’ awon enia Re Lyrics
Next: Hymn 416 F’ awon enia Re t’ o lo ’simi Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 585 Jesu, o ha le je be pe Lyrics
  • Hymn 148 Baba wa orun npe Lyrics
  • Hymn 538 Pase ’bukun Re t’oke wa Lyrics
  • Hymn 289 Bibeli mimo t’ orun Lyrics
  • Hymn 12 A gboju soke si O Lyrics
  • Hymn 592 Enyin ’ranse Kristi Lyrics
  • Hymn 229 Jesu t’o ku, k’ o gb’ aiye la Lyrics
  • Hymn 275 Emi Mimo ‘Dada orun Lyrics
  • Hymn 523 Awa ti gbe o sin Lyrics
  • Hymn 361 Jesu, ma to wa Lyrics
  • Hymn 385 Gbekele Olorun re Lyrics
  • Hymn 87 Wa enyin oloto Lyrics
  • Hymn 267 Emi Eleda, nipa Re Lyrics
  • Hymn 204 Wo Odagutan ti o ru Lyrics
  • Hymn 20 ’Wo Imole ! larin okun aiye Lyrics
  • Hymn 132 Lo wasu ihinrere mi Lyrics
  • Hymn 373 Didan l’ opagun wa Lyrics
  • Hymn 468 Ore kan mbe fun omode Lyrics
  • Hymn 388 Yo awon ti nsegbe, sajo eni nku Lyrics
  • Hymn 23 Oluwa, ojo t’ o fun wa pin Lyrics
  • Hymn 79 Ojo ayo nlanla na de Lyrics
  • Hymn 583 Otosi elese ni mi Lyrics
  • Hymn 397 Olorun ogbon at’ ore Lyrics
  • Hymn 1 Ji, okan mi, ba orun ji Lyrics
  • Hymn 249 Ile ewa wonni, b’ o ti dara to Lyrics
  • Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics
  • Hymn 351 Ore- ofe! b’ o ti dun to Lyrics
  • Hymn 158 Olorun, fi opa Re Lyrics
  • Hymn 292 Iwo Oro Olorun Lyrics
  • Hymn 214 Leba iboji Jesu mi Lyrics
  • Hymn 53 Oluwa agbara fohun Lyrics
  • Hymn 304 Baba, b’ ife Re ni, lati Lyrics
  • Hymn 452 Wa, Emi Mimo, sokale Lyrics
  • Hymn 377 Duro, duro fun Jesu Lyrics
  • Hymn 273 Wa mi si wa, Emi Mimo Lyrics
  • Hymn 316 Isun kan wa t’ o kun f’ eje Lyrics
  • Hymn 461 Opo ikan omi Lyrics
  • Hymn 334 Oruko kan mbe ti mo fe Lyrics
  • Hymn 136 Krist’, ki ’joba Re de Lyrics
  • Hymn 412 Mura, elese, lati gbon Lyrics
  • Hymn 264 Olurapada wa, k’On to Lyrics
  • Hymn 564 L’oko Jesu, gbogbo ekun yio wole Lyrics
  • Hymn 305 Jesu l’ Olusagutan mi Lyrics
  • Hymn 45 Wa, enyin olope, wa Lyrics
  • Hymn 211 Olugbala mi ha gbogbe Lyrics
  • Hymn 167 Ki se l’ainireti Lyrics
  • Hymn 394 Jesu, mase je k’a simi Lyrics
  • Hymn 398 Emi at’ ara ile mi Lyrics
  • Hymn 344 Jesu, Iwo ni a nwo Lyrics
  • Hymn 529 Jesu Oluwa ni ’se Lyrics
  • Hymn 565 Alleluya! Orin t’o dun Lyrics
  • Hymn 17 L’ oju ale, ’gbat ’orun wo Lyrics
  • Hymn 384 Gba aiye mi, Oluwa Lyrics
  • Hymn 145 Elese;- – mo nfe ’bukun Lyrics
  • Hymn 47 Ojo ibukun y’o siro Lyrics
  • Hymn 367 E ma te siwaju, Kristian ologun Lyrics
  • Hymn 70 Wo ! Oluwa l’ awosanma Lyrics
  • Hymn 418 Awa f’ ori bale fun Lyrics
  • Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics
  • Hymn 379 Omo Olorun nlo s’ ogun Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version