Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics

Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

APA I.

1 Salem t’orun, Ilu ’bukun,
T’o kun fun ’fe at’ayo,
Ti a f’okuta aye ko,
Ni orun giga loke,
Pel’ ogun angeli yika,
T’o nsokale b’ iyawo.

2 Lat’ ode orun lohun
L’o ti wo aso ogo,
T’o ye Eniti o fe o,
Ao sin o f’oko re;
Gbogbo ita at’ odi re
Je kiki oso wura.

3 Ilekun re ndan fun pearli
Nwon wa ni sisi titi;
Awon oloto nwo ’nu re
Nip’ eje Olugbala,
Awon t’o farada ’ponju
’Tori oruko Jesu.

4 Wahala at’ iponju nla
L’o s’okuta re lewa,
Jesu papa l’ Eni to won
S’ipo ti o gbe dara,
Ife inu Re sa ni pe,
K’ a le s’ afin Re l’ oso.

5 Ogo at’ ola fun Baba,
Ogo at’ ola f’ Omo,
Ogo at’ ola fun Emi,
Metalokan titi lai;
At’ aiyeraiye Okanna,
Bakanna titi aiye. Amin.

APA II.

1 Kristi n’ ipile t’o daju,
Krist l’Ori at’ Igunle,
Asayan at’ Iyebiye,
O so gbogbo Ijo lu;
Iranwo Sioni Mimo,
Igbekele re titi.

2 Si Tempili yi l’ a npe O,
Jo wa loni, Oluwa;
Ni opo inurere Re,
Gbo ebe enia Re,
Ma da ekun ibukun Re
Sinu ile yi titi.

3 Fun awon omo Re l’ ebun
Ti nwon ba toro nihin,
Ore ti nwon ba si ri gba,
K’o ma je ti won titi;
Nikehin ninu ogo Re,
Kin won ma ba O joba.

4 Ogo at’ola fun Baba
Ogo at’ola f’ Omo,
Ogo at’ola fun Emi,
Metalokan titi lai,
At’ aiyeraiye, Okanna,
Bakanna titi aiye. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 576 Kristi n’ ipile wa Lyrics
Next: Hymn 578 Ife l’ Olorun, anu Re Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 337 Awa ko orin ife Re Lyrics
  • Hymn 491 Mase huwa ese Lyrics
  • Hymn 598 E korin s’Olorun wa Lyrics
  • Hymn 272 Wa, Parakliti mimo Lyrics
  • Hymn 544 Wa, iwo Isun ibukun Lyrics
  • Hymn 92 Olorun, t’ odun t’ o koja Lyrics
  • Hymn 87 Wa enyin oloto Lyrics
  • Hymn 27 Ojo isimi Olorun Lyrics
  • Hymn 203 E gb’ ohun ife at’ anu Lyrics
  • Hymn 32 Nigbawo Olugbala mi Lyrics
  • Hymn 255 Jerusalem t’ orun Lyrics
  • Hymn 405 Tire l’ola Baba Lyrics
  • Hymn 421 Gbo, okan mi, bi Angeli ti nkorin Lyrics
  • Hymn 104 Ese won ti da to! Lyrics
  • Hymn 274 Emi Mimo sokale Lyrics
  • Hymn 359 Jesu, ’Wo ti mbo agbo Re Lyrics
  • Hymn 98 Olorun Betel, eniti Lyrics
  • Hymn 85 O de, Kristi Oluwa Lyrics
  • Hymn 108 Bi ’gba ti Mose gbe ejo Lyrics
  • Hymn 338 Okan mi, Oluwa ni Lyrics
  • Hymn 476 Awon kekeke wo l’ eyi Lyrics
  • Hymn 567 Ni ile Olorun Lyrics
  • Hymn 531 Oluwa, a wa ’do Re Lyrics
  • Hymn 460 Bi osun gbege eti ’do Lyrics
  • Hymn 586 Ma koja mi, Olugbala Lyrics
  • Hymn 463 Jesu onirele Lyrics
  • Hymn 441 Tal’ awa ba ha to lo Lyrics
  • Hymn 53 Oluwa agbara fohun Lyrics
  • Hymn 120 Oluwa y’o tip e to Lyrics
  • Hymn 244 Olorun goke lo Lyrics
  • Hymn 205 Olorun fe araiye Lyrics
  • Hymn 534 Wakati adura didun Lyrics
  • Hymn 124 Ilu t’ o dara po l’ aiye Lyrics
  • Hymn 343 Fe enikeji re Lyrics
  • Hymn 445 Jesu, Iwo l’ a gbohun si Lyrics
  • Hymn 364 A! alejo at’ ero Lyrics
  • Hymn 287 Olorun Olodumare Lyrics
  • Hymn 397 Olorun ogbon at’ ore Lyrics
  • Hymn 188 Olorun, Baba mi, ’Wo npe Lyrics
  • Hymn 570 Oluwa, Iwo wadi mi Lyrics
  • Hymn 417 Wa k’a da m’ awon ore wa Lyrics
  • Hymn 559 E gbe ohun ayo at’ iyin ga Lyrics
  • Hymn 292 Iwo Oro Olorun Lyrics
  • Hymn 565 Alleluya! Orin t’o dun Lyrics
  • Hymn 63 L’ eba odo Jordani ni Lyrics
  • Hymn 420 Olori Ijo t’ orun Lyrics
  • Hymn 353 Jesu, mo gb’ agbelebu mi Lyrics
  • Hymn 311 Alafia, li laiye ese yi Lyrics
  • Hymn 541 Lekan k’a to tuka Lyrics
  • Hymn 332 Olugbala mi, ife Re Lyrics
  • Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics
  • Hymn 79 Ojo ayo nlanla na de Lyrics
  • Hymn 172 Bi mo ti ri laisawawi Lyrics
  • Hymn 514 Gbat’ a kun fun banuje Lyrics
  • Hymn 149 Jina s’ile orun Lyrics
  • Hymn 545 Wa, Jesu fi ara han Lyrics
  • Hymn 14 Ife Re da wa si loni Lyrics
  • Hymn 222 Oluwa ji loto Lyrics
  • Hymn 253 Jerusalem ibi ayo Lyrics
  • Hymn 389 Okan are, ile kan mbe Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version