Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 202 Okun l’ ale, tutu n’ ile Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 202 Okun l’ ale, tutu n’ ile Lyrics

Hymn 202 Okun l’ ale, tutu n’ ile Lyrics

December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 202 Okun l’ ale, tutu n’ ile Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

APA I

1 Okun l’ ale, tutu n’ ile,
Nibi Kristi wole,
Ogun Re bi iro eje,
Ninu ’waya ija.

2 “Baba gb’ ago kikoro yi,
B’ o ba se ife Re;
Bi beko, Emi o si mu,
Ife Re ni k’ a se.”

3 Elese lo wo l’ agbala,
Eje mimo wonni:
O r’ eru wuwo ni fun o,
O re ’ra ’le fun o.

4 Ko lati gbe agbelebu,
Se ife ti Baba;
Nigba idanwo sunmole,
Ji, sora, gbadura. Amin.

APA II

1 Ki Jesu ha nikan jiya,
K’ araiye lo lofo?
Iya mbe f’olukuluku;
Iya si mbe fun mi.

2 Em’ o ru agbelebu mi,
Tit’ iku y’o gba mi;
’Gban, ngo lo ’le lo d’ ade,
‘Tor’ ade mbe fun mi.

3 Nile ita Kristali na,
Leba ese Jesu,
Ngo f’ ade wura mi lele;
Ngo yin oruko Re.

4 A! agbelebu! A! ade!
A! ojo ajinde!
Enyin Angel, e sokale,
Wag be okan mi lo. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 201 Oke kan mbe jina rere Lyrics
Next: Hymn 203 E gb’ ohun ife at’ anu Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 292 Iwo Oro Olorun Lyrics
  • Hymn 462 Oluso- agutan l’ Olugbala wa Lyrics
  • Hymn 507 Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi Lyrics
  • Hymn 320 ’Gba mo le ka oye mi re Lyrics
  • Hymn 551 Je k’a f’ohun kan korin Lyrics
  • Hymn 138 ’Ranse Olorun, e ma kede Re Lyrics
  • Hymn 280 Mimo, mimo, mimo! Olodumare! Lyrics
  • Hymn 589 Wo bi awa enia Re Lyrics
  • Hymn 294 Iwe kan wa ti kika re Lyrics
  • Hymn 412 Mura, elese, lati gbon Lyrics
  • Hymn 38 K’ ojo ’simi yi to tan Lyrics
  • Hello world!
  • Hymn 264 Olurapada wa, k’On to Lyrics
  • Hymn 59 Wa iwo Jesu t’ a nreti Lyrics
  • Hymn 177 Jesu, emi o fi okan mi fun O Lyrics
  • Hymn 584 Enit’ O la ’ju afoju Lyrics
  • Hymn 413 Enyin wo ni tempili Re Lyrics
  • Hymn 45 Wa, enyin olope, wa Lyrics
  • Hymn 562 A korin s’ Omo Olorun Lyrics
  • Hymn 289 Bibeli mimo t’ orun Lyrics
  • Hymn 521 Odun nyipo, o nji emi Lyrics
  • Hymn 200 Ogo ni fun Jesu Lyrics
  • Hymn 309 Mo f’ emi mi sabe Lyrics
  • Hymn 27 Ojo isimi Olorun Lyrics
  • Hymn 64 Iwo Onidajo Lyrics
  • Hymn 186 Ji ’se Re nde, Jesu! Lyrics
  • Hymn 419 Oba awon eni mimo Lyrics
  • Hymn 12 A gboju soke si O Lyrics
  • Hymn 96 Baba ki m’ ya odun yi Lyrics
  • Hymn 397 Olorun ogbon at’ ore Lyrics
  • Hymn 121 Olorun mi bojuwo mi Lyrics
  • Hymn 134 Lati erekusu Lyrics
  • Hymn 350 Oluwa, Iwo ha wipe Lyrics
  • Hymn 576 Kristi n’ ipile wa Lyrics
  • Hymn 436 Ojo Ko; ase na leyi Lyrics
  • Hymn 383 Mo simi le Jesu Lyrics
  • Hymn 541 Lekan k’a to tuka Lyrics
  • Hymn 57 Wo oju sanma ohun ni Lyrics
  • Hymn 324 Tire lailai l’ awa se Lyrics
  • Hymn 62 Sunm’ odo wa, Emmanuel Lyrics
  • Hymn 390 Mo f’ara Mi fun o Lyrics
  • Hymn 305 Jesu l’ Olusagutan mi Lyrics
  • Hymn 110 Enyin enia Olorun Lyrics
  • Hymn 135 Gbo iro efufu, lat’ ona jijin Lyrics
  • Hymn 37 Didun n’ise na, Oba mi Lyrics
  • Hymn 152 Alaimo ni emi Lyrics
  • Hymn 476 Awon kekeke wo l’ eyi Lyrics
  • Hymn 175 Otosi elese, e wa Lyrics
  • Hymn 574 Oro alafia Lyrics
  • Hymn 192 Iwo elese, Emi nfi anu pe Lyrics
  • Hymn 369 Ese d’ eru? wo, Jesu ni Lyrics
  • Hymn 22 Jesu, bukun wa k’ a to lo Lyrics
  • Hymn 234 Jesu, wa sarin wa Lyrics
  • Hymn 414 F’ awon enia Re Lyrics
  • Hymn 71 Olorun ! kini mo ri yi ! Lyrics
  • Hymn 398 Emi at’ ara ile mi Lyrics
  • Hymn 442 Oluwa, mo mba O pade nihin Lyrics
  • Hymn 434 Mo nkebi on ongbe Lyrics
  • Hymn 368 Amona okan at’ Oga Lyrics
  • Hymn 518 Lala alagbase tan Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version