Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 595 F’ awon Ijo ti nsimi Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 595 F’ awon Ijo ti nsimi Lyrics

Hymn 595 F’ awon Ijo ti nsimi Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 595 F’ awon Ijo ti nsimi Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 F’ awon Ijo ti nsimi,
Awa Ijo t’ aiye;
A f’ iyin gbogbo fun O,
Jesu Olubukun;
Oluwa, O ti segun,
Ki nwon ba le segun;
’Mole ade ogo won,
Lat’ odo Re wa ni.

St. Anderu.

A yin O, fun ’ranse Re,
Ti o ko j’ ipe Re:
T’o mu arakonrin re
Wa, lati ri Kristi;
Pese okan wa sile,
K’a sona lodun yi,
K’a m’ awon ara wa wa,
Lati ri bibo Re.

St. Tomasi.

A yin O, fun ’ranse Re,
T’ iseyemeji re,
F’ ese ’gbagbo wa mule,
T’ o si fi ’fe Re han;
Oluwa f’ alafia
F’awon ti nreti Re;
Je k’a mo O lotito,
L’ enia at’ Olorun.

St. Stefanu.

A yin O, fun ’ranse Re,
Ajeriku ’kini:
Eni, ninu wahala,
T’o nkepe Olorun;
Oluwa, b’o ba kan wa
Lati jiya fun O,
L’aiye, je k’a jeri Re,
L’ orun, je k’a gb’ ade.

St. Johannu Onihinrere.

A yin O, fun ’ranse
L’ erekusu Patmo,
A yin O, f’ eri toto,
Ti o je nipa Re.
A yin O, fun iran na,
Ti O fihan fun wa;
A o fi suru duro,
K’ a le ka wa mo won.

Ojo awon Omo were ti a pa.

A yin O, f’awon ewe,
Ajeriku mimo;
A si won lowo ogun,
Lo sibi isimi;
Rakeli, ma sokun mo,
Nwon bo lowo ’rora:
F’ okan ailetan fun wa,
K’ a gb’ ade bi ti won.

Iyipada ti St. Paulu.

A yin O, fun imole
At’ ohun lat’ orun,
A si yin O, fun iran,
Ti abinuku ri;
Ati fun ’yipada re,
A fi ogo fun O
Jo, tan ina Emi Re,
Sinu okunkun wa.

St. Mattia.

Oluwa, Iwo t’ o wa.
Pel’ awon t’ o pejo;
Iwo t’o yan Mattia
Lati ropo Juda:
A’ mbe O, gba Ijo Re
Lowo eke woli;
Rant’ ileri Re, Jesu,
Pelu ’jo Re dopin.

St. Marku.

A yin O fun ’ranse Re,
T’ Iwo f’ agbara fun;
Enit’ ihinrere re
Mu orin ’segun dun;
Ati n’nu ailera wa,
Jo je agbara wa;
Je k’a s’ eso ninu Re,
Iwo Ajara wa.

St. Filippi ati St. Jakobu.

A nyin O fun ’ranse Re,
Fillipi amona;
Ati f’ arakonrin Re,
Se wa l’ arakonrin;
Masai je k’ a le mo O,
Ona, Iye, Oto;
K’ a jeju ko idanwo,
Titi ao fi segun.

St. Barnaba.

A nyin O, fun Barnaba,
Enit’ ife Re mu
K’o ko ’hun aiye sile,
K’o wa ohun orun;
Bi aiye ti ngbile si,
Ran emi Re si wa,
Ki itunu Re toto,
Tan bo gbogbo aiye.

St. Johannu Baptisti.

A yin O, f’ Oni- baptis,
Asaju Oluwa;
Elija toto ni ’se,
Lati tun ona se.
Woli t’o ga julo ni,
O ri owuro Re;
Se wa l’ alabukunfun,
Ti nreti ojo Re.

St. Peteru.

A yin O, fun ’ranse Re,
Ogboiya ninu won;
O sebu nigba meta,
O ronupiwada;
Pelu awon alufa,
Lati toju agbo;
Si fun won ni igboiya
At’ itara pelu.

St. Jakobu.

A yin O, fun ’ranse Re,
Eniti Herod pa;
O mu ago iya Re,
O mu oro Re se;
K’ a ko iwara sile,
K’ a fi suru duro;
K’a ka iya si ayo,
B’o ba fa wa mo O.

St. Bartolomeu.

A yin O, fun ’ranse Re,
Eni oloto ni;
Enit’ oju Re ti ri,
Labe ’gi opoto.
Jo, se wa l’ alailetan,
Israeli toto;
Ki O le ma ba wa gbe,
K’ O ma bo okan wa.

St. Matteu.

A yin O, fun ’ranse Re,
T’o so ti ibi Re;
T’o ko ’hun aiye sile,
T’o yan ona iya;
Jo, da okan wa nide,
Lowo ife owo;
Je k’a le je ipe Re,
K’a nde k’a tele O.

St. Luku.

A yin O, f’ onisegun,
Ti ihinrere re,
Fi O han b’ Onisegun,
At’ Abanidaro;
Jo, f’ororo iwosan,
Si okan gbogbo wa,
At’ ikunra ’yebiye,
Kun wa nigbagbogbo.

St. Simoni ati St. Juda.

F’awon iranse Re yi,
A yin O, Oluwa;
Ife kanna l’o mu won,
Lati gb’ ona mimo;
Awa iba le jo won,
Lati gbe Jesu ga:
Ki ife so wa sokan,
K’a de ibi ’simi.

IPARI (GENERAL ENDING).

Apostili, Woli, Martyr,
Awon egbe mimo;
Nwon ko dekun orin won,
Nwon wo aso ala;
F’ awonyi t’o ti koja,
A yin O, Oluwa;
Ao tele ipase won,
A o si ma sin O.

Iyin f’ Olorun Baba,
At’ Olorun Omo,
Olorun Emi Mimo,
Metalokan Mimo;
Awon ti a ra pada,
Y’o teriba fun O;
Tire l’ ola, at’ ipa,
At’ ogo, Olorun. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 594 E tun won ko fun mi ki ngbo Lyrics
Next: Hymn 596 Orun ododo, jowo la Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 444 ‘K’ On to de, – je k’oro yi Lyrics
  • Hymn 292 Iwo Oro Olorun Lyrics
  • Hymn 18 Baba, a tun pade l’oko Jesu Lyrics
  • Hymn 122 Elese, wa sodo Jesu Lyrics
  • Hymn 343 Fe enikeji re Lyrics
  • Hymn 331 B’ oruko Jesu ti dun to Lyrics
  • Hymn 238 Oluwa wa orun Lyrics
  • Hymn 9 Jesu, Orun ododo Lyrics
  • Hymn 363 Olorun emi wa, at’ igbala wa Lyrics
  • Hymn 175 Otosi elese, e wa Lyrics
  • Hymn 316 Isun kan wa t’ o kun f’ eje Lyrics
  • Hymn 386 Sise tori oru mbo Lyrics
  • Hymn 269 Emi Mimo sokale Lyrics
  • Hymn 25 Ojo ‘simi at’ ayo Lyrics
  • Hymn 19 Ero di| dun kan| nso Lyrics
  • Hymn 549 K’ore- ofe Krist’ Oluwa Lyrics
  • Hymn 529 Jesu Oluwa ni ’se Lyrics
  • Hymn 333 Ife orun, alailegbe Lyrics
  • Hymn 178 F’ ore- ofe Re ba wa gbe Lyrics
  • Hymn 216 Simi okan mi, ni ireti Lyrics
  • Hymn 517 Bi agogo ofo t’ a nlu Lyrics
  • Hymn 194 Gbogb’ ogo, iyin, ola Lyrics
  • Hymn 77 Eyin Angel l’ orun ogo Lyrics
  • Hymn 251 Je ki m’ni ’po mi lodo Re Lyrics
  • Hymn 271 Emi anu, oto, ife Lyrics
  • Hymn 556 Fun anu to po b’iyanrin Lyrics
  • Hymn 587 Olugbala gbohun mi Lyrics
  • Hymn 246 E gbo iro orin ayo orun Lyrics
  • Hymn 64 Iwo Onidajo Lyrics
  • Hymn 247 Iwo ti goke lo Lyrics
  • Hymn 562 A korin s’ Omo Olorun Lyrics
  • Hymn 183 Gbogbo eje eran Lyrics
  • Hymn 103 Kabiyesi ! Isun ’bukun Lyrics
  • Hymn 306 Oluwa Olorun mi, se ’fe Re Lyrics
  • Hymn 593 Ore- ofe! ohun Lyrics
  • Hymn 546 Si ohun ti a gbin Lyrics
  • Hello world!
  • Hymn 326 Ona ara l’Olorun wa Lyrics
  • Hymn 413 Enyin wo ni tempili Re Lyrics
  • Hymn 511 So itan kanna fun mi Lyrics
  • Hymn 514 Gbat’ a kun fun banuje Lyrics
  • Hymn 303 Aigbagbo, bila ! temi l’ Oluwa Lyrics
  • Hymn 152 Alaimo ni emi Lyrics
  • Hymn 195 Ma gesin lo l’olanla Re Lyrics
  • Hymn 347 Wo! b’ o ti dun to lati ri Lyrics
  • Hymn 569 Ise gbogbo ti awa nse Lyrics
  • Hymn 516 Igba asale ti dun to Lyrics
  • Hymn 113 Irawo wo l’eyi Lyrics
  • Hymn 301 Oju kan mbe ti ki togbe Lyrics
  • Hymn 153 Ko to k’ awon mimo beru Lyrics
  • Hymn 124 Ilu t’ o dara po l’ aiye Lyrics
  • Hymn 248 O ti lo. Awosanma Lyrics
  • Hymn 14 Ife Re da wa si loni Lyrics
  • Hymn 274 Emi Mimo sokale Lyrics
  • Hymn 49 Iwo mbo wa, Oluwa mi Lyrics
  • Hymn 440 ‘Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re Lyrics
  • Hymn 362 Larin ewu at’ osi Lyrics
  • Hymn 484 Wa, ba wa jeun, Oluwa Lyrics
  • Hymn 448 Nihinyi n’ isimi gbe wa Lyrics
  • Hymn 429 Wo orison ohun rere Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version