Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 569 Ise gbogbo ti awa nse Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 569 Ise gbogbo ti awa nse Lyrics

Hymn 569 Ise gbogbo ti awa nse Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 569 Ise gbogbo ti awa nse Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Ise gbogbo ti awa nse,
Ni Olorun ti ri;
Ero gbogbo t’o wa ninu,
Ni Olorun si mo.

2 A ko le f’ese wa pamo,
Gbogbo won l’ O ti mo:
A npuro, a ntan ’ra wa je,
B’ a ro pe ko mo won.

3 Ohun gbogbo han ni gbangba,
Ni oju Olorun;
Okunkun ati imole,
Si ri bakanna fun.

4 Olorun, je k’a ranti pe,
Oju re si ri wa;
Si je ki awa k’o beru
Lati dese si O. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 568 Okan mi, yin Oba orun Lyrics
Next: Hymn 570 Oluwa, Iwo wadi mi Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 371 Jesu mimo, Ore airi Lyrics
  • Hymn 396 Funrugbin lowuro Lyrics
  • Hymn 510 Isimi wa l’orun, ko si l’aiye yi Lyrics
  • Hymn 12 A gboju soke si O Lyrics
  • Hymn 133 E fi oju iyonu wo Lyrics
  • Hymn 444 ‘K’ On to de, – je k’oro yi Lyrics
  • Hymn 379 Omo Olorun nlo s’ ogun Lyrics
  • Hymn 140 Jesu y’o joba ni gbogbo Lyrics
  • Hymn 241 Wo Asegun b’o ti goke Lyrics
  • Hymn 23 Oluwa, ojo t’ o fun wa pin Lyrics
  • Hymn 286 Baba, Eleda wa Lyrics
  • Hymn 55 Oluwa mbo; aiye o mi Lyrics
  • Hymn 419 Oba awon eni mimo Lyrics
  • Hymn 283 Baba orun, ’jinle ’fe Re Lyrics
  • Hymn 303 Aigbagbo, bila ! temi l’ Oluwa Lyrics
  • Hymn 401 Aye si mbe! ile Odagutan Lyrics
  • Hymn 384 Gba aiye mi, Oluwa Lyrics
  • Hymn 544 Wa, iwo Isun ibukun Lyrics
  • Hymn 80 Wo ! gbogbo ile okunkun Lyrics
  • Hymn 414 F’ awon enia Re Lyrics
  • Hymn 323 Nihin l’ ayida wa Lyrics
  • Hymn 346 Alabukun ni fun ife Lyrics
  • Hymn 407 Emi okan wa npe Lyrics
  • Hymn 289 Bibeli mimo t’ orun Lyrics
  • Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics
  • Hymn 178 F’ ore- ofe Re ba wa gbe Lyrics
  • Hymn 399 E wa s’apakan, k’e simi die Lyrics
  • Hymn 481 Gba Jesu f’ ite Re sile Lyrics
  • Hymn 151 Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re Lyrics
  • Hymn 48 Gbo ’gbe ayo ! Oluwa de Lyrics
  • Hymn 308 Laifoiya l’apa Jesu Lyrics
  • Hymn 191 Oluwa mo gbo pe Lyrics
  • Hymn 370 Emi ‘ba le f’ iwa pele Lyrics
  • Hymn 527 Olorun, awa fe Lyrics
  • Hymn 483 Olorun, orin eniti Lyrics
  • Hymn 77 Eyin Angel l’ orun ogo Lyrics
  • Hymn 433 Li oru ibanuje ni Lyrics
  • Hymn 593 Ore- ofe! ohun Lyrics
  • Hymn 291 Jesu, oro Re ye Lyrics
  • Hymn 536 Jesu, nib’ eni Re pade Lyrics
  • Hymn 74 Gbe ori nyin s’ oke, enyin Lyrics
  • Hymn 152 Alaimo ni emi Lyrics
  • Hymn 431 Jesu ayo okan gbogbo Lyrics
  • Hymn 115 E yo Jesu joba Lyrics
  • Hymn 364 A! alejo at’ ero Lyrics
  • Hymn 138 ’Ranse Olorun, e ma kede Re Lyrics
  • Hymn 157 Bi mo ti kunle, Oluwa Lyrics
  • Hymn 244 Olorun goke lo Lyrics
  • Hymn 313 Igbagbo mi wo O Lyrics
  • Hymn 386 Sise tori oru mbo Lyrics
  • Hymn 571 Teruteru t’ iyanu ni Lyrics
  • Hymn 321 Nipa Ife Olugbala Lyrics
  • Hymn 503 Ire t’ a su ni Eden Lyrics
  • Hymn 169 Apata aiyeraiye Lyrics
  • Hymn 113 Irawo wo l’eyi Lyrics
  • Hymn 24 Olorun wa Orun Lyrics
  • Hymn 397 Olorun ogbon at’ ore Lyrics
  • Hymn 585 Jesu, o ha le je be pe Lyrics
  • Hymn 61 Ara mi fun’ rugbin rere Lyrics
  • Hymn 403 Eredi irokeke yi Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version