Hymn 438 Kil’o le w’ese mi nu Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 Kil’o le w’ese mi nu,
Ko si, lehin eje Jesu;
Ki l’o tun le wo mi san,
Ko si, lehin eje Jesu.
A! eje yebiye
T’o mu mi fun bi sno,
Ko s’isun miran mo,
Ko si, lehin eje Jesu.
2 Fun ‘wenumo mi, nko ri
Nkan mi, lehin eje Jesu;
Ohun ti mo gbekele
Fun ‘dariji, l’ eje Jesu.
A! eje ‘yebibye, &c.;
3 Etutu f’ese ko si,
Ko si, lehin eje Jesu;
Ise rere kan ko si,
Ko si, lehin eje Jesu.
A! eje ‘yebiye, &c.;
4 Gbogbo igbekele mi,
Ireti mi, l’ eje Jesu;
Gbogbo ododo mi ni
Eje, kiki eje Jesu.
A! eje yebiye, &c.; Amin..