Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 427 Oluwa orun on aiye Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 427 Oluwa orun on aiye Lyrics

Hymn 427 Oluwa orun on aiye Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 427 Oluwa orun on aiye Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Oluwa orun on aiye,
‘Wo n’ iyin at’ ope ye fun;
Bawo l’ a ba ti fe O to,
Onibu ore?

2 Orun ti nran, at’ afefe,
Gbogbo eweko nso ‘fe Re;
‘Wo l’ O nmu irugbin dara,
Onibu ore

3 Fun ara lile wa gbogbo,
Fun gbogbo ibukun aiye,
Awa yin O, a si dupe,
Onibu ore

4 O ko du wa li Omo Re,
O fi fun aiye ese wa,
O si f’ebun gbogbo pelu,
Onibu ore

5 O fun wa l’ Emi Mimo Re,
Emi iye at’ agbara,
O rojo ekun bukun Re
Le wa lori.

6 Fun idariji ese wa,
Ati fun ireti orun,
Kil’ ohun t’ a ba fi fun O?
Onibu ore.

7 Owo ti a nna, ofo ni,
Sugbon eyi t’ a fi fun O,
O je isura tit’ aiye,
Onibu ore.

8 Ohun t’ a bun O, Oluwa,
‘Wo o sa nle pada fun wa;
Layo l’a o ta O lore,
Onibu ore.

9 Ni odo Re lati san wa,
Olorun Olodumare;
Jeki k’ a le ba O gbe titi,
Onibu Ore. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics
Next: Hymn 428 Ohun t’a fi fun O Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 317 Ohun ogo Re l’ a nrohin Lyrics
  • Hymn 190 Ibu anu ! O le je Lyrics
  • Hymn 419 Oba awon eni mimo Lyrics
  • Hymn 399 E wa s’apakan, k’e simi die Lyrics
  • Hymn 97 Odun miran ti koja Lyrics
  • Hymn 156 Ro iponju mi, Oluwa Lyrics
  • Hymn 588 Gb’ adura wa, Oba aiye Lyrics
  • Hymn 74 Gbe ori nyin s’ oke, enyin Lyrics
  • Hymn 245 Onigbagbo, e wa Lyrics
  • Hymn 282 Olorun Metalokan Lyrics
  • Hymn 570 Oluwa, Iwo wadi mi Lyrics
  • Hymn 106 Olorun Oluwa aiye Lyrics
  • Hymn 133 E fi oju iyonu wo Lyrics
  • Hymn 506 Olorun mi, ’Wo l’ em’ o pe Lyrics
  • Hymn 409 Loni ni Jesu pe Lyrics
  • Hymn 398 Emi at’ ara ile mi Lyrics
  • Hymn 461 Opo ikan omi Lyrics
  • Hymn 150 Nigba nwon kehin si Sion Lyrics
  • Hymn 542 K’ Olorun so o Lyrics
  • Hymn 202 Okun l’ ale, tutu n’ ile Lyrics
  • Hymn 521 Odun nyipo, o nji emi Lyrics
  • Hymn 288 Mo f’ iyin ailopin Lyrics
  • Hymn 559 E gbe ohun ayo at’ iyin ga Lyrics
  • Hymn 335 Jesu Oluwa, a fe O Lyrics
  • Hymn 463 Jesu onirele Lyrics
  • Hymn 116 Ji, apa Olorun, k’ o ji Lyrics
  • Hymn 14 Ife Re da wa si loni Lyrics
  • Hymn 301 Oju kan mbe ti ki togbe Lyrics
  • Hymn 169 Apata aiyeraiye Lyrics
  • Hymn 58 Yo, enyin onigbagbo Lyrics
  • Hymn 458 Jesu, ’Wo onirele Lyrics
  • Hymn 109 Jesu, b’ ise tab’ iya ni Lyrics
  • Hymn 285 Iyin ainipekun Lyrics
  • Hymn 498 Mo ti seleri, Jesu Lyrics
  • Hymn 113 Irawo wo l’eyi Lyrics
  • Hymn 380 Baba mi, ‘gba mba / nsako lo Lyrics
  • Hymn 255 Jerusalem t’ orun Lyrics
  • Hymn 244 Olorun goke lo Lyrics
  • Hymn 253 Jerusalem ibi ayo Lyrics
  • Hymn 552 E je k’a f’ inu didun Lyrics
  • Hymn 582 Igba aro ati ayo Lyrics
  • Hymn 278 Si O, Olutunu orun Lyrics
  • Hymn 375 Ha! Egbe mi, e w’ asia Lyrics
  • Hymn 551 Je k’a f’ohun kan korin Lyrics
  • Hymn 445 Jesu, Iwo l’ a gbohun si Lyrics
  • Hymn 338 Okan mi, Oluwa ni Lyrics
  • Hymn 362 Larin ewu at’ osi Lyrics
  • Hymn 123 Baba orun ! emi fe wa Lyrics
  • Hymn 515 A! nwon ti gun s’ ebute Lyrics
  • Hymn 489 Jesu, a w’ odo Re Lyrics
  • Hymn 194 Gbogb’ ogo, iyin, ola Lyrics
  • Hymn 545 Wa, Jesu fi ara han Lyrics
  • Hymn 321 Nipa Ife Olugbala Lyrics
  • Hymn 514 Gbat’ a kun fun banuje Lyrics
  • Hymn 550 E je k’a yin Olorun wa Lyrics
  • Hymn 450 Jesu, ’Wo ti mbo agbo Re Lyrics
  • Hymn 341 Ki nfe O si, Kristi Lyrics
  • Hymn 484 Wa, ba wa jeun, Oluwa Lyrics
  • Hymn 290 Bawo ni awon ewe wa Lyrics
  • Hymn 166 Kristi t’ agbelebu l’ orin wa Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version