Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 7 Wa s’ adura oro Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 7 Wa s’ adura oro Lyrics

Hymn 7 Wa s’ adura oro Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 7 Wa s’ adura oro Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Wa s’ adura oro,
Kunle k’ a gbadura;
Adura ni opa Kristian,
Lati b’ Olorun rin.

2 Losan, wole labe
Apat’ aiyeraiye;
Itura ojiji Re dun
Nigbat’ orun ba mu.

3 Je ki gbogbo ile
Wa gbadura l’ ale
Ki ile wa di t’ Olorun
Ati ’bode orun.

4 Nigbat’ o d’ oganjo,
Je k’ a wi l’ emi pe
Mo sun, sugbon okan mi ji
Lati ba O sona. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 6 Krist, Ologo, Olola Lyrics
Next: Hymn 8 Imole oro, didun yi Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 252 Olor’ Alufa giga kan Lyrics
  • Hymn 71 Olorun ! kini mo ri yi ! Lyrics
  • Hymn 398 Emi at’ ara ile mi Lyrics
  • Hymn 464 Mo fe ki ndabi Jesu Lyrics
  • Hymn 4 Oluwa mi, mo njade lo Lyrics
  • Hymn 100 Alakoso ti orun Lyrics
  • Hymn 58 Yo, enyin onigbagbo Lyrics
  • Hymn 261 A nsoro ile ’bukun ni Lyrics
  • Hymn 576 Kristi n’ ipile wa Lyrics
  • Hymn 402 Ojo nsure, o nkoja Lyrics
  • Hymn 321 Nipa Ife Olugbala Lyrics
  • Hymn 243 Kristi, lehin isegun Lyrics
  • Hymn 535 Sa wo ite anu Lyrics
  • Hymn 84 Ayo kun okan wa loni Lyrics
  • Hymn 45 Wa, enyin olope, wa Lyrics
  • Hymn 329 Ngo feran Re, ‘wo odi mi Lyrics
  • Hymn 298 Ma gbadura Lyrics
  • Hymn 208 Agbelebu ni ere mi Lyrics
  • Hymn 294 Iwe kan wa ti kika re Lyrics
  • Hymn 470 Gba Jesu wo tempili lo Lyrics
  • Hymn 101 Olorun wa, je k’ iyin Re Lyrics
  • Hymn 444 ‘K’ On to de, – je k’oro yi Lyrics
  • Hymn 352 Ewa ’tanna oro kutu Lyrics
  • Hymn 287 Olorun Olodumare Lyrics
  • Hymn 47 Ojo ibukun y’o siro Lyrics
  • Hymn 153 Ko to k’ awon mimo beru Lyrics
  • Hymn 489 Jesu, a w’ odo Re Lyrics
  • Hymn 333 Ife orun, alailegbe Lyrics
  • Hymn 273 Wa mi si wa, Emi Mimo Lyrics
  • Hymn 494 Enikan mbe t’ O feran wa Lyrics
  • Hymn 460 Bi osun gbege eti ’do Lyrics
  • Hymn 43 Yin Olorun, yin lailai Lyrics
  • Hymn 196 Hosanna s’Omo Dafidi Lyrics
  • Hymn 64 Iwo Onidajo Lyrics
  • Hymn 138 ’Ranse Olorun, e ma kede Re Lyrics
  • Hymn 179 Baba alanu t’o fe wa Lyrics
  • Hymn 203 E gb’ ohun ife at’ anu Lyrics
  • Hymn 67 Jesu kigbe pe, “Emi de Lyrics
  • Hymn 235 Ojo ’mole l’eyi Lyrics
  • Hymn 137 Wa jade larin Keferi p’ Oluwa l’ Oba Lyrics
  • Hymn 277 Emi orun, gb’ adura wa Lyrics
  • Hymn 382 Iranse Oluwa Lyrics
  • Hymn 374 Enyin ero, nibo l’ e nlo Lyrics
  • Hymn 348 Alafia ni f’ okan na Lyrics
  • Hymn 9 Jesu, Orun ododo Lyrics
  • Hymn 193 Tani le so t’ayo ti mbe Lyrics
  • Hymn 588 Gb’ adura wa, Oba aiye Lyrics
  • Hymn 156 Ro iponju mi, Oluwa Lyrics
  • Hymn 490 K’ awa to pari eko wa Lyrics
  • Hymn 367 E ma te siwaju, Kristian ologun Lyrics
  • Hymn 357 Kristian, ma ti ’wa ’simi Lyrics
  • Hymn 371 Jesu mimo, Ore airi Lyrics
  • Hymn 148 Baba wa orun npe Lyrics
  • Hymn 289 Bibeli mimo t’ orun Lyrics
  • Hymn 387 Ao sise! ao sise! om- Olorun ni wa Lyrics
  • Hymn 496 Oluwa, k’ a ha w’ odo Re Lyrics
  • Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics
  • Hymn 393 Wa, ma sise Lyrics
  • Hymn 139 Iyin f’Eni Mimo julo Lyrics
  • Hymn 492 Olusagutan mi Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version