Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 7 Wa s’ adura oro Lyrics

Hymn 7 Wa s’ adura oro Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Wa s’ adura oro,
Kunle k’ a gbadura;
Adura ni opa Kristian,
Lati b’ Olorun rin.

2 Losan, wole labe
Apat’ aiyeraiye;
Itura ojiji Re dun
Nigbat’ orun ba mu.

3 Je ki gbogbo ile
Wa gbadura l’ ale
Ki ile wa di t’ Olorun
Ati ’bode orun.

4 Nigbat’ o d’ oganjo,
Je k’ a wi l’ emi pe
Mo sun, sugbon okan mi ji
Lati ba O sona. Amin.

Exit mobile version