Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 527 Olorun, awa fe Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 527 Olorun, awa fe Lyrics

Hymn 527 Olorun, awa fe Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 527 Olorun, awa fe Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Olorun, awa fe
Ile t’ola Re wa;
Ayo ibugbe Re
Ju gbogbo ayo lo.

2 Ile adura ni,
Fun awa omo Re;
Jesu, O wa nibe,
Lati gbo ebe wa.

3 Awa fe ase Re,
Kil’ o dun to l’ aiye;
Nib’ awon oloto,
Nri O nitosi won.

4 Awa fe oro Re,
Oro alafia;
T’itunu at’ iye,
Oro ayo titi.

5 A fe korin anu,
T’a nri gba l’aiye yi;
Sugbon awa fe mo
Orin ayo t’orun.

6 Jesu, Oluwa wa,
Busi ’fe wa nihin;
Mu wa de ’nu ogo,
Lati yio O titi. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 526 Isin Jesu ni ’funni Lyrics
Next: Hymn 528 Gbogbo enyin ti ngbe aiye Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 54 Gbo ohun olore Lyrics
  • Hymn 261 A nsoro ile ’bukun ni Lyrics
  • Hymn 373 Didan l’ opagun wa Lyrics
  • Hymn 160 Baba ma yi oju kuro Lyrics
  • Hymn 447 Duro, omo ogun Lyrics
  • Hymn 441 Tal’ awa ba ha to lo Lyrics
  • Hymn 104 Ese won ti da to! Lyrics
  • Hymn 322 Mo gbohun Jesu t’ o wipe Lyrics
  • Hymn 66 Oru bu koja tan Lyrics
  • Hymn 515 A! nwon ti gun s’ ebute Lyrics
  • Hymn 502 Olorun, gb’ okan mi loni Lyrics
  • Hymn 544 Wa, iwo Isun ibukun Lyrics
  • Hymn 247 Iwo ti goke lo Lyrics
  • Hymn 5 Wa s’odo mi, Oluwa mi Lyrics
  • Hymn 296 Bibel’ iwe aiyeraiye! Lyrics
  • Hymn 509 O s’ ohun t’o ti mi loju Lyrics
  • Hymn 153 Ko to k’ awon mimo beru Lyrics
  • Hymn 439 Ase ife orun Lyrics
  • Hymn 592 Enyin ’ranse Kristi Lyrics
  • Hymn 4 Oluwa mi, mo njade lo Lyrics
  • Hymn 203 E gb’ ohun ife at’ anu Lyrics
  • Hymn 552 E je k’a f’ inu didun Lyrics
  • Hymn 136 Krist’, ki ’joba Re de Lyrics
  • Hymn 382 Iranse Oluwa Lyrics
  • Hymn 147 Iwo low’ enit’ ire nsan Lyrics
  • Hymn 219 Jesu ye; titi aiye Lyrics
  • Hymn 3 Nigbat’ imole owuro Lyrics
  • Hymn 248 O ti lo. Awosanma Lyrics
  • Hymn 21 K’ a to sun, Olugba wa Lyrics
  • Hymn 192 Iwo elese, Emi nfi anu pe Lyrics
  • Hymn 177 Jesu, emi o fi okan mi fun O Lyrics
  • Hymn 579 Ese mi po bi irawo Lyrics
  • Hymn 328 A ba le n’igbagbo aye Lyrics
  • Hymn 405 Tire l’ola Baba Lyrics
  • Hymn 107 E funpe na kikan Lyrics
  • Hymn 221 Eyi l’ojo ajinde Lyrics
  • Hello world!
  • Hymn 129 Olorun, gbogbo araiye Lyrics
  • Hymn 264 Olurapada wa, k’On to Lyrics
  • Hymn 44 A f’ope f’ Olorun Lyrics
  • Hymn 88 Lehin odun die Lyrics
  • Hymn 29 Oluwa ojo isimi Lyrics
  • Hymn 459 Ojo oni lo tan Lyrics
  • Hymn 35 Akoko odun at’ osu Lyrics
  • Hymn 39 Emi Olorun alaye Lyrics
  • Hymn 587 Olugbala gbohun mi Lyrics
  • Hymn 61 Ara mi fun’ rugbin rere Lyrics
  • Hymn 483 Olorun, orin eniti Lyrics
  • Hymn 567 Ni ile Olorun Lyrics
  • Hymn 128 Eni t’ o joko low’ otun Lyrics
  • Hymn 370 Emi ‘ba le f’ iwa pele Lyrics
  • Hymn 336 ’Gbat aiye yi ba koja Lyrics
  • Hymn 493 Hosanna! e korin soke Lyrics
  • Hymn 130 Gbo orin ’yin dida aiye Lyrics
  • Hymn 387 Ao sise! ao sise! om- Olorun ni wa Lyrics
  • Hymn 397 Olorun ogbon at’ ore Lyrics
  • Hymn 290 Bawo ni awon ewe wa Lyrics
  • Hymn 347 Wo! b’ o ti dun to lati ri Lyrics
  • Hymn 82 ’Gba Jehofah da aiye Lyrics
  • Hymn 386 Sise tori oru mbo Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version