Hymn 454 Emi Olorun wa Lyrics December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook Hymn 454 Emi Olorun wa Lyrics Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook 1 Emi Olorun wa, Baptis’ awon wonyi: Ba won da majemu mimo, We won kuro l’ ese. 2 Fo ’pa Esu tutu, We won ’nu eje Re; Baba, Omo, Emi Mimo, So won di Omo Re. Amin.