Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 454 Emi Olorun wa Lyrics

Hymn 454 Emi Olorun wa Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Emi Olorun wa,
Baptis’ awon wonyi:
Ba won da majemu mimo,
We won kuro l’ ese.

2 Fo ’pa Esu tutu,
We won ’nu eje Re;
Baba, Omo, Emi Mimo,
So won di Omo Re. Amin.

Exit mobile version