Skip to content

Mon - Sat: 8.00 - 18.00

04463235323

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics

Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Jesu, ba Ijo Re gbe,
Samona at’ odi re,
B’o ti nla ’danwo koja;
Awa mbe O, gbo tiwa.

2 F’ owo ife Re yi ka,
Dabobo lowo ota,
Tu ninu nigba ibi;
Awa mbe O, gbo tiwa.

3 M’ eko at’ iwa re mo;
Je k’o fi suru duro;
K’o simi le ’leri Re;
Awa mbe O, gbo tiwa.

4 Pelu re lojo gbogbo,
K’o bo lowo isina;
K’o ma sise fun yin Re;
Awa mbe O, gbo tiwa.

5 K’ ohun re ma ja goro,
N’ ikilo ’dajo ti mbo;
Ni siso ife Jesu:
Awa mbe O, gbo tiwa.

6 Wa tun ibaje re se,
Wa tun Tempili Re ko,
Fi ara Re han nibe,
Awa mbe O, gbo tiwa.

7 Wad a gbogbo ide re
Mu ’lara at’ ija tan,
M’ alafia orun wa,
Awa mbe O, gbo tiwa.

8 Mu gbogbo oran re to;
Ma je k’owo Esu te;
Ki aiye ma le tan je:
Awa mbe O, gbo tiwa.

9 K’ eko re je okanna,
N’nu otito at’ ife;
K’o fa opo s’ igbagbo
Awa mbe O, gbo tiwa.

10 K’o ma toju alaini,
K’o si ma wa asako,
At’ onirobinuje:
Awa mbe O, gbo tiwa.

11 Ma je k’ife re tutu,
M’ awon oluso gboiya,
S’ agbara y’ agbo Re ka:
Awa mbe O, gbo tiwa.

12 K’ awon alufa ma bo;
Kin won j’ oluso toto,
Lati ma to Ijo Re.
Awa mbe O, gbo tiwa.

13 Ki nwon se bi nwon ti nso,
K’ nwon f’apere mimo han
Bi asaju agbo Re,
Awa mbe O, gbo tiwa.

14 F’ or’- ofe Enit’ o ku
At’ ife Baba ba gbe;
K’ Emi ma samona re:
Awa mbe O, gbo tiwa.

15 We gbogbo arun re nu;
L’ eru on ’yemeji lo,
Mu ’segun re de Kankan.
Awa mbe O, gbo tiwa.

16 Ran lowo nigba awe,
Tit’ ise re o pari,
T’ Oko- yawo y’o si de:
Awa mbe O, gbo tiwa.

17 Nigbana k’O se logo,
Ati ni ailabawon,
L’ewa didan t’o ye O.
Awa mbe O, gbo tiwa.

18 Mu ye, ki on ba le pin
N’nu aye t’ Iwo npese;
Lai, k’o n’ ibukun nibe.
Awa mbe O, gbo tiwa.

Post navigation

Previous: Hymn 420 Olori Ijo t’ orun Lyrics
Next: Hymn 441 Tal’ awa ba ha to lo Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics
  • Hymn 482 Omode, e sunm’ Olorun Lyrics
  • Hymn 44 A f’ope f’ Olorun Lyrics
  • Hymn 414 F’ awon enia Re Lyrics
  • Hymn 94 B’ orun l’ aiduro ti rin Lyrics
  • Hymn 95 Olorun at’ ireti mi Lyrics
  • Hymn 104 Ese won ti da to! Lyrics
  • Hymn 142 Kristi sun f’ elese Lyrics
  • Hymn 163 Oluwa, b’ agbowode ni Lyrics
  • Hymn 221 Eyi l’ojo ajinde Lyrics
  • Hymn 488 Ose, Ose rere Lyrics
  • Hymn 194 Gbogb’ ogo, iyin, ola Lyrics
  • Hymn 260 Paradise! Paradise! Lyrics
  • Hymn 521 Odun nyipo, o nji emi Lyrics
  • Hymn 81 Gbo eda orun nkorin Lyrics
  • Hymn 478 Ona kan l’o ntoka sorun Lyrics
  • Hymn 96 Baba ki m’ ya odun yi Lyrics
  • Hymn 67 Jesu kigbe pe, “Emi de Lyrics
  • Hymn 148 Baba wa orun npe Lyrics
  • Hymn 597 Iyin, ola, ogo, ’bukun Lyrics
  • Hymn 444 ‘K’ On to de, – je k’oro yi Lyrics
  • Hymn 179 Baba alanu t’o fe wa Lyrics
  • Hymn 21 K’ a to sun, Olugba wa Lyrics
  • Hymn 237 ’Bugbe Re ti l’ewa to Lyrics
  • Hymn 297 Tori Mi at’ Ihinrere Lyrics
  • Hymn 325 Om’ Olorun a ko ri O Lyrics
  • Hymn 446 Eyi l’ ase nla Jehofa Lyrics
  • Hymn 510 Isimi wa l’orun, ko si l’aiye yi Lyrics
  • Hymn 160 Baba ma yi oju kuro Lyrics
  • Hymn 591 Oluwa, emi sa ti gbohun Re Lyrics
  • Hymn 13 Orun fere wo na Lyrics
  • Hymn 585 Jesu, o ha le je be pe Lyrics
  • Hymn 516 Igba asale ti dun to Lyrics
  • Hymn 73 Ojo dajo, ojo eru! Lyrics
  • Hymn 306 Oluwa Olorun mi, se ’fe Re Lyrics
  • Hymn 559 E gbe ohun ayo at’ iyin ga Lyrics
  • Hymn 345 Ara, e je k’ a jumo rin Lyrics
  • Hymn 66 Oru bu koja tan Lyrics
  • Hymn 427 Oluwa orun on aiye Lyrics
  • Hymn 280 Mimo, mimo, mimo! Olodumare! Lyrics
  • Hymn 31 Bi mo ti yo, lati gb’ oro Lyrics
  • Hymn 560 E wole f’Oba, Ologo julo Lyrics
  • Hymn 530 Oluwa, mo de ’bi ’te Re Lyrics
  • Hymn 155 Jesu, jo ranti mi Lyrics
  • Hymn 365 Ngo se foiya ojo ibi Lyrics
  • Hymn 558 Wo, owon Olurapada Lyrics
  • Hymn 504 Jesu f’ ara han nitoto Lyrics
  • Hymn 165 Si pepe Oluwa Lyrics
  • Hymn 527 Olorun, awa fe Lyrics
  • Hymn 284 E fi ogo fun Baba Lyrics
  • Hymn 434 Mo nkebi on ongbe Lyrics
  • Hymn 189 Pada asako s’ile re Lyrics
  • Hymn 97 Odun miran ti koja Lyrics
  • Hymn 4 Oluwa mi, mo njade lo Lyrics
  • Hymn 469 Orun tanmole Lyrics
  • Hymn 590 Wo oro t’o dun julo Lyrics
  • Hymn 248 O ti lo. Awosanma Lyrics
  • Hymn 554 Niwaju ite Jehofa Lyrics
  • Hymn 151 Jesu mi, mu mi gb’ ohun Re Lyrics
  • Hymn 423 Tani o gbe Jakob dide Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version