Skip to content

Mon - Sat: 8.00 - 18.00

04463235323

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics

Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Emi ’bukun ti a nsin
Pelu Baba at’ Oro,
Olorun aiyeraiye;
Emi Mimo, gbo ti wa.

2 Emi Mimo, ’Daba orun,
Iri tin se lat’ oke,
Emi ’ye at’ ina ’fe;
Emi Mimo, gbo ti wa.

3 Isun ipa at’ imo,
Ogbon at’ iwa- mimo,
Oye, imoran, eru;
Emi Mimo, gbo ti wa.

4 Isun ife, Alafia,
Suru, ibisi ’gbagbo,
’Reti, ayo ti ki tan;
Emi Mimo, gbo ti wa.

5 Emi Afonahan ni,
Emi tin mu ’mole wa,
Emi agbara gbogbo;
Emi Mimo, gbo ti wa.

6 ’Wo t’ o mu Wundia bi,
Eni t’ orun t’ aiye mbo,
T’a ran lati tun wa bi;
Emi Mimo, gbo ti wa.

7 ’Wo ti Jesu t’ oke ran
Wa tu enia Re ninu,
Kin won ma ba nikan wa;
Emi Mimo, gbo ti wa.

8 ’Wo t’O nf’ ore kun Ijo,
T’O nfi ife Baba han,
T’O nmu k’o ma ri Jesu;
Emi Mimo, gbo ti wa.

9 Iwo ti nf’ onje iye,
At’ otito na bo wa,
Ani, On t’O ku fun wa;
Emi Mimo, gbo ti wa.

10 F’ ebun meje Re fun ni,
Ogbon, lati m’ Olorun,
Ipa lati ko ota;
Emi Mimo, gbo ti wa.

11 Pa ese run lokan wa,
To ife wa si ona,
B’a ban se O, mu suru;
Emi Mimo, gbo ti wa.

12 Gbe wa dide, b’a subu,
Ati nigba idanwo,
Sa pe wa pada pele;
Emi Mimo, gbo ti wa.

13 Wa, k’O mu ailera le,
F’ igboya fun alare,
Ko wa l’ oror t’a o so;
Emi Mimo, gbo ti wa.

14 Wa ran okan wa lowo,
Lati mo otito Re,
Ki ’fe wa le ma gbona;
Emi Mimo, gbo ti wa.

15 Pa wa mo l’ona toro
Baw a wi nigb’a nsako,
Ba wa bebe l’ adura,
Emi Mimo, gbo ti wa.

16 Eni Mimo, Olufe,
Wa gbe inu okan wa;
Ma fi wa sile titi:
Emi Mimo, gbo ti wa. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 260 Paradise! Paradise! Lyrics
Next: Hymn 281 Baba oke Orun Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 492 Olusagutan mi Lyrics
  • Hymn 210 Enyin ti nkoja Lyrics
  • Hymn 157 Bi mo ti kunle, Oluwa Lyrics
  • Hymn 97 Odun miran ti koja Lyrics
  • Hymn 24 Olorun wa Orun Lyrics
  • Hymn 561 Gbogbo aiye, gbe Jesu ga Lyrics
  • Hymn 296 Bibel’ iwe aiyeraiye! Lyrics
  • Hymn 181 Olorun ’yanu ! ona kan Lyrics
  • Hymn 311 Alafia, li laiye ese yi Lyrics
  • Hymn 590 Wo oro t’o dun julo Lyrics
  • Hymn 446 Eyi l’ ase nla Jehofa Lyrics
  • Hymn 106 Olorun Oluwa aiye Lyrics
  • Hymn 288 Mo f’ iyin ailopin Lyrics
  • Hymn 379 Omo Olorun nlo s’ ogun Lyrics
  • Hymn 563 Ewe ti Oba orun Lyrics
  • Hymn 71 Olorun ! kini mo ri yi ! Lyrics
  • Hymn 424 Baba, niwaju ite Re Lyrics
  • Hymn 175 Otosi elese, e wa Lyrics
  • Hymn 293 Olorun l’ abo eni Re Lyrics
  • Hymn 77 Eyin Angel l’ orun ogo Lyrics
  • Hymn 380 Baba mi, ‘gba mba / nsako lo Lyrics
  • Hymn 146 Jesu, agbara mi Lyrics
  • Hymn 245 Onigbagbo, e wa Lyrics
  • Hymn 394 Jesu, mase je k’a simi Lyrics
  • Hymn 290 Bawo ni awon ewe wa Lyrics
  • Hymn 121 Olorun mi bojuwo mi Lyrics
  • Hymn 348 Alafia ni f’ okan na Lyrics
  • Hymn 443 Sumohin, k’o gba Ara Oluwa Lyrics
  • Hymn 99 Oluwa alafia wa Lyrics
  • Hymn 511 So itan kanna fun mi Lyrics
  • Hymn 154 A f’ ayo ro ore- ofe Lyrics
  • Hymn 556 Fun anu to po b’iyanrin Lyrics
  • Hymn 359 Jesu, ’Wo ti mbo agbo Re Lyrics
  • Hymn 553 Ji! ko orin Mose Lyrics
  • Hymn 180 Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin Lyrics
  • Hymn 515 A! nwon ti gun s’ ebute Lyrics
  • Hymn 198 E je k’a to Jesu wa lo Lyrics
  • Hymn 5 Wa s’odo mi, Oluwa mi Lyrics
  • Hymn 21 K’ a to sun, Olugba wa Lyrics
  • Hymn 239 Kini ’simi ayo ailopin ni Lyrics
  • Hymn 436 Ojo Ko; ase na leyi Lyrics
  • Hymn 507 Jesu ’Wo n’ ibi sadi mi Lyrics
  • Hymn 543 Fi ibukun Re tu wa ka Lyrics
  • Hymn 133 E fi oju iyonu wo Lyrics
  • Hymn 578 Ife l’ Olorun, anu Re Lyrics
  • Hymn 383 Mo simi le Jesu Lyrics
  • Hymn 53 Oluwa agbara fohun Lyrics
  • Hymn 494 Enikan mbe t’ O feran wa Lyrics
  • Hymn 381 Ninu oru ibanuje Lyrics
  • Hymn 522 Itanna t’o bo ’gbe l’ aso Lyrics
  • Hymn 527 Olorun, awa fe Lyrics
  • Hymn 535 Sa wo ite anu Lyrics
  • Hymn 586 Ma koja mi, Olugbala Lyrics
  • Hymn 179 Baba alanu t’o fe wa Lyrics
  • Hymn 263 Kukuru l’oj’ aiye wa Lyrics
  • Hymn 497 Emi o lo sodo Jesu Lyrics
  • Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics
  • Hymn 315 F’eru re f’ afefe Lyrics
  • Hymn 345 Ara, e je k’ a jumo rin Lyrics
  • Hymn 266 Emi Olorun mi Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version