Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 418 Awa f’ ori bale fun Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 418 Awa f’ ori bale fun Lyrics

Hymn 418 Awa f’ ori bale fun Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 418 Awa f’ ori bale fun Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Awa f’ ori bale fun | O Jesu,
’Wo ti s’ Olori Ijo awon | enia Re,
Ijo ti mbe laiye yi, ati lo| run pelu:
Alle| luya!

2 ’Wo t’o ku, t’o si jin| de fun wa,
T’o mbe lodo Baba bi Ala| gbawi wa,
K’ ogo at’ olanla | je Tire:
Alle| luya!

3 Ati li ojo nla Pen| tikosti,
Ti o ran Parakliti | si aiye
Olutunu nla Re ti mba wa gbe:
Alle| luya!

4 Lat’ ori ite Re l’ o| ke orun,
L’O si nwo gbogbo awon o| jise Re,
T’O si nsike gbogbo awon Aje| riku Re:
Alle| luya!

5 A fi iyin at’ olanla f’ o| ruko Re,
N’tori iku gbogbo awon o| jise Re,
Ni gbogbo ile Yo| ruba yi:
Alle| luya! Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 417 Wa k’a da m’ awon ore wa Lyrics
Next: Hymn 419 Oba awon eni mimo Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 265 ‘Gbani t’ Olorun sokale Lyrics
  • Hymn 317 Ohun ogo Re l’ a nrohin Lyrics
  • Hymn 422 Alabukun n’nu Jesu Lyrics
  • Hymn 193 Tani le so t’ayo ti mbe Lyrics
  • Hymn 96 Baba ki m’ ya odun yi Lyrics
  • Hymn 323 Nihin l’ ayida wa Lyrics
  • Hymn 487 Ile- eko ojo ’simi Lyrics
  • Hymn 571 Teruteru t’ iyanu ni Lyrics
  • Hymn 499 Tire titi lai l’ awa se Lyrics
  • Hymn 516 Igba asale ti dun to Lyrics
  • Hymn 24 Olorun wa Orun Lyrics
  • Hymn 569 Ise gbogbo ti awa nse Lyrics
  • Hymn 256 Ile ayo kan wa Lyrics
  • Hymn 100 Alakoso ti orun Lyrics
  • Hymn 29 Oluwa ojo isimi Lyrics
  • Hymn 538 Pase ’bukun Re t’oke wa Lyrics
  • Hymn 142 Kristi sun f’ elese Lyrics
  • Hymn 415 Tal’ awon wonyi b’ irawo Lyrics
  • Hymn 257 Oke kan mbe t’ o ga Lyrics
  • Hymn 348 Alafia ni f’ okan na Lyrics
  • Hymn 472 Jehofa! Olorun ogo Lyrics
  • Hymn 83 Ayo b’ aiye ! Oluwa de Lyrics
  • Hymn 199 Ara, e wa ba mi sofo Lyrics
  • Hymn 392 Tan ‘mole Re si wa Lyrics
  • Hymn 527 Olorun, awa fe Lyrics
  • Hymn 394 Jesu, mase je k’a simi Lyrics
  • Hymn 567 Ni ile Olorun Lyrics
  • Hymn 596 Orun ododo, jowo la Lyrics
  • Hymn 270 Adaba orun, sokale Lyrics
  • Hymn 475 Gbati Samuel ji Lyrics
  • Hymn 581 Awa fe ohun aiye yi Lyrics
  • Hymn 428 Ohun t’a fi fun O Lyrics
  • Hymn 208 Agbelebu ni ere mi Lyrics
  • Hymn 118 Lat’ oke tutu Grinland Lyrics
  • Hymn 222 Oluwa ji loto Lyrics
  • Hymn 333 Ife orun, alailegbe Lyrics
  • Hymn 381 Ninu oru ibanuje Lyrics
  • Hymn 273 Wa mi si wa, Emi Mimo Lyrics
  • Hymn 258 Lehin aiye okunkun yi Lyrics
  • Hymn 120 Oluwa y’o tip e to Lyrics
  • Hymn 351 Ore- ofe! b’ o ti dun to Lyrics
  • Hymn 561 Gbogbo aiye, gbe Jesu ga Lyrics
  • Hymn 78 Onigbagbo, e bu s’ ayo Lyrics
  • Hymn 514 Gbat’ a kun fun banuje Lyrics
  • Hymn 91 Ojo ati akoko nlo Lyrics
  • Hymn 243 Kristi, lehin isegun Lyrics
  • Hymn 27 Ojo isimi Olorun Lyrics
  • Hymn 190 Ibu anu ! O le je Lyrics
  • Hymn 336 ’Gbat aiye yi ba koja Lyrics
  • Hymn 526 Isin Jesu ni ’funni Lyrics
  • Hymn 177 Jesu, emi o fi okan mi fun O Lyrics
  • Hymn 573 Baba wa, Olodumare Lyrics
  • Hymn 240 Mo mo p’ Oludande mi mbe Lyrics
  • Hymn 312 N’ irumi at’ iji aiye Lyrics
  • Hymn 201 Oke kan mbe jina rere Lyrics
  • Hymn 212 ’Wo t’ o mbebe f’ ota Re Lyrics
  • Hymn 179 Baba alanu t’o fe wa Lyrics
  • Hymn 23 Oluwa, ojo t’ o fun wa pin Lyrics
  • Hymn 592 Enyin ’ranse Kristi Lyrics
  • Hymn 473 Mo fe gbo itan kanna Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version