Hymn 444 ‘K’ On to de, – je k’oro yi Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 ‘K’ On to de, – je k’oro yi
Ma dun titi l’eti re;
Je ki sa die t’o ku
Han gbangba daju fun o;
Ronu b’orun on ile
Ti d’ ehin gbat’ O ba de.’
2 Gbat’ awon ti a feran
Bo si ‘simi won l’oke,
T’o jo pe aiye wa pin,
Ti adun re si koro;
E dakun, e ma b’ohun,
Kiki ‘k’ On to de’ sa ni.
3 Ibanuje yi wa ka;
A ha fe k’o dinku bi?
Gbogbo of aiye yi,
Iku, ofo on ‘boji
Nso jeje pe, ‘K’ On t’o de.
4 Wo tabil’ ife t’a te,
Mu waini, si j’akara;
‘Ranti didun, – k’ Oluwa
To pew a s’ onje orun;
‘Mi lat’ aiye, ‘mi l’orun,
Nwon pinya tit’ On fi de.’ Amin.