Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics

Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 577 Salem t’orun, Ilu ’bukun Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

APA I.

1 Salem t’orun, Ilu ’bukun,
T’o kun fun ’fe at’ayo,
Ti a f’okuta aye ko,
Ni orun giga loke,
Pel’ ogun angeli yika,
T’o nsokale b’ iyawo.

2 Lat’ ode orun lohun
L’o ti wo aso ogo,
T’o ye Eniti o fe o,
Ao sin o f’oko re;
Gbogbo ita at’ odi re
Je kiki oso wura.

3 Ilekun re ndan fun pearli
Nwon wa ni sisi titi;
Awon oloto nwo ’nu re
Nip’ eje Olugbala,
Awon t’o farada ’ponju
’Tori oruko Jesu.

4 Wahala at’ iponju nla
L’o s’okuta re lewa,
Jesu papa l’ Eni to won
S’ipo ti o gbe dara,
Ife inu Re sa ni pe,
K’ a le s’ afin Re l’ oso.

5 Ogo at’ ola fun Baba,
Ogo at’ ola f’ Omo,
Ogo at’ ola fun Emi,
Metalokan titi lai;
At’ aiyeraiye Okanna,
Bakanna titi aiye. Amin.

APA II.

1 Kristi n’ ipile t’o daju,
Krist l’Ori at’ Igunle,
Asayan at’ Iyebiye,
O so gbogbo Ijo lu;
Iranwo Sioni Mimo,
Igbekele re titi.

2 Si Tempili yi l’ a npe O,
Jo wa loni, Oluwa;
Ni opo inurere Re,
Gbo ebe enia Re,
Ma da ekun ibukun Re
Sinu ile yi titi.

3 Fun awon omo Re l’ ebun
Ti nwon ba toro nihin,
Ore ti nwon ba si ri gba,
K’o ma je ti won titi;
Nikehin ninu ogo Re,
Kin won ma ba O joba.

4 Ogo at’ola fun Baba
Ogo at’ola f’ Omo,
Ogo at’ola fun Emi,
Metalokan titi lai,
At’ aiyeraiye, Okanna,
Bakanna titi aiye. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 576 Kristi n’ ipile wa Lyrics
Next: Hymn 578 Ife l’ Olorun, anu Re Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 547 Olorun, a so oro Re Lyrics
  • Hymn 278 Si O, Olutunu orun Lyrics
  • Hymn 239 Kini ’simi ayo ailopin ni Lyrics
  • Hymn 38 K’ ojo ’simi yi to tan Lyrics
  • Hymn 249 Ile ewa wonni, b’ o ti dara to Lyrics
  • Hymn 37 Didun n’ise na, Oba mi Lyrics
  • Hymn 523 Awa ti gbe o sin Lyrics
  • Hymn 308 Laifoiya l’apa Jesu Lyrics
  • Hymn 404 Nigbat’ idanwo yi mi ka Lyrics
  • Hymn 590 Wo oro t’o dun julo Lyrics
  • Hymn 335 Jesu Oluwa, a fe O Lyrics
  • Hymn 36 Ayo l’ ojo ’simi fun mi Lyrics
  • Hymn 430 Mo nlo; talaka Mi mbe lodo nyin Lyrics
  • Hymn 252 Olor’ Alufa giga kan Lyrics
  • Hymn 4 Oluwa mi, mo njade lo Lyrics
  • Hymn 207 ’Gbati mo ri agbelebu Lyrics
  • Hymn 551 Je k’a f’ohun kan korin Lyrics
  • Hymn 337 Awa ko orin ife Re Lyrics
  • Hymn 210 Enyin ti nkoja Lyrics
  • Hymn 343 Fe enikeji re Lyrics
  • Hymn 84 Ayo kun okan wa loni Lyrics
  • Hymn 137 Wa jade larin Keferi p’ Oluwa l’ Oba Lyrics
  • Hymn 186 Ji ’se Re nde, Jesu! Lyrics
  • Hymn 60 ’Mole t’o da gbogbo nkan Lyrics
  • Hymn 215 Isimi awon mimo Lyrics
  • Hymn 476 Awon kekeke wo l’ eyi Lyrics
  • Hymn 200 Ogo ni fun Jesu Lyrics
  • Hymn 296 Bibel’ iwe aiyeraiye! Lyrics
  • Hymn 496 Oluwa, k’ a ha w’ odo Re Lyrics
  • Hymn 445 Jesu, Iwo l’ a gbohun si Lyrics
  • Hymn 491 Mase huwa ese Lyrics
  • Hymn 596 Orun ododo, jowo la Lyrics
  • Hymn 251 Je ki m’ni ’po mi lodo Re Lyrics
  • Hymn 508 A fe ri Jesu Lyrics
  • Hymn 206 Wakati didun ni fun mi Lyrics
  • Hymn 286 Baba, Eleda wa Lyrics
  • Hymn 226 Krist, Oluwa ji loni, Halleluya Lyrics
  • Hymn 293 Olorun l’ abo eni Re Lyrics
  • Hymn 70 Wo ! Oluwa l’ awosanma Lyrics
  • Hymn 25 Ojo ‘simi at’ ayo Lyrics
  • Hymn 510 Isimi wa l’orun, ko si l’aiye yi Lyrics
  • Hymn 530 Oluwa, mo de ’bi ’te Re Lyrics
  • Hymn 178 F’ ore- ofe Re ba wa gbe Lyrics
  • Hymn 423 Tani o gbe Jakob dide Lyrics
  • Hymn 435 Odo Agutan Olorun Lyrics
  • Hymn 464 Mo fe ki ndabi Jesu Lyrics
  • Hymn 383 Mo simi le Jesu Lyrics
  • Hymn 459 Ojo oni lo tan Lyrics
  • Hymn 177 Jesu, emi o fi okan mi fun O Lyrics
  • Hymn 330 Jesu, kiki ironu Re Lyrics
  • Hymn 272 Wa, Parakliti mimo Lyrics
  • Hymn 8 Imole oro, didun yi Lyrics
  • Hymn 593 Ore- ofe! ohun Lyrics
  • Hymn 17 L’ oju ale, ’gbat ’orun wo Lyrics
  • Hymn 382 Iranse Oluwa Lyrics
  • Hymn 455 Baba, Apat’ agbara wa Lyrics
  • Hymn 521 Odun nyipo, o nji emi Lyrics
  • Hymn 244 Olorun goke lo Lyrics
  • Hymn 184 Jesu, l’ara Re l’awa nwo Lyrics
  • Hymn 87 Wa enyin oloto Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version