Skip to content

Mon - Sat: 8.00 - 18.00

04463235323

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 537 Je ki ilekun aitase Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 537 Je ki ilekun aitase Lyrics

Hymn 537 Je ki ilekun aitase Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 537 Je ki ilekun aitase Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Je ki ilekun aitase,
Si fun ise wa, Oluwa,
Ti o si ki o ti mo,
Ilekun ’wole oro Re.

2 F’ owo ina to ete won,
Ti nfi ’lana Re han aiye;
F’ ife mimo si aiya won,
Ti Olorun at’ enia.

3 F’ itara fun iranse Re,
T’ ohun kan ko le mu tutu;
Bi nwon si tin tan oro Re,
Bukun imo at’ ise won.

4 Ran Emi Re lat’ oke wa,
Ma je ki agbara Re pin:
Tit’ irira o fi pari,
Ti gbogbo ija o si tan. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 520 Awon mimo, lala pari Lyrics
Next: Hymn 541 Lekan k’a to tuka Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 312 N’ irumi at’ iji aiye Lyrics
  • Hymn 50 Ojo ’dajo on ’binu Lyrics
  • Hymn 20 ’Wo Imole ! larin okun aiye Lyrics
  • Hymn 166 Kristi t’ agbelebu l’ orin wa Lyrics
  • Hymn 155 Jesu, jo ranti mi Lyrics
  • Hymn 482 Omode, e sunm’ Olorun Lyrics
  • Hymn 470 Gba Jesu wo tempili lo Lyrics
  • Hymn 35 Akoko odun at’ osu Lyrics
  • Hymn 262 Oru ko si l’orun Lyrics
  • Hymn 124 Ilu t’ o dara po l’ aiye Lyrics
  • Hymn 106 Olorun Oluwa aiye Lyrics
  • Hymn 556 Fun anu to po b’iyanrin Lyrics
  • Hymn 110 Enyin enia Olorun Lyrics
  • Hymn 214 Leba iboji Jesu mi Lyrics
  • Hymn 272 Wa, Parakliti mimo Lyrics
  • Hymn 149 Jina s’ile orun Lyrics
  • Hymn 284 E fi ogo fun Baba Lyrics
  • Hymn 27 Ojo isimi Olorun Lyrics
  • Hymn 4 Oluwa mi, mo njade lo Lyrics
  • Hymn 125 Ma sise lo, mase sare Lyrics
  • Hymn 304 Baba, b’ ife Re ni, lati Lyrics
  • Hymn 552 E je k’a f’ inu didun Lyrics
  • Hymn 129 Olorun, gbogbo araiye Lyrics
  • Hymn 311 Alafia, li laiye ese yi Lyrics
  • Hymn 7 Wa s’ adura oro Lyrics
  • Hymn 439 Ase ife orun Lyrics
  • Hymn 188 Olorun, Baba mi, ’Wo npe Lyrics
  • Hymn 481 Gba Jesu f’ ite Re sile Lyrics
  • Hymn 101 Olorun wa, je k’ iyin Re Lyrics
  • Hymn 99 Oluwa alafia wa Lyrics
  • Hymn 378 Omogun Krist, dide Lyrics
  • Hymn 295 Baba orun, nin’ oro Re Lyrics
  • Hymn 8 Imole oro, didun yi Lyrics
  • Hymn 525 Ara, iwo si| waju wa lo Lyrics
  • Hymn 455 Baba, Apat’ agbara wa Lyrics
  • Hymn 365 Ngo se foiya ojo ibi Lyrics
  • Hymn 518 Lala alagbase tan Lyrics
  • Hymn 471 Olorun ite ogo Re Lyrics
  • Hymn 63 L’ eba odo Jordani ni Lyrics
  • Hymn 583 Otosi elese ni mi Lyrics
  • Hymn 594 E tun won ko fun mi ki ngbo Lyrics
  • Hymn 399 E wa s’apakan, k’e simi die Lyrics
  • Hymn 466 Gbat’ O ba de, gbat’ O ba de Lyrics
  • Hymn 480 Jesu t’ o wa l’ oke orun Lyrics
  • Hymn 315 F’eru re f’ afefe Lyrics
  • Hymn 186 Ji ’se Re nde, Jesu! Lyrics
  • Hymn 226 Krist, Oluwa ji loni, Halleluya Lyrics
  • Hymn 273 Wa mi si wa, Emi Mimo Lyrics
  • Hymn 46 Olorun ’fe, Isun anu Lyrics
  • Hymn 219 Jesu ye; titi aiye Lyrics
  • Hymn 13 Orun fere wo na Lyrics
  • Hymn 59 Wa iwo Jesu t’ a nreti Lyrics
  • Hymn 590 Wo oro t’o dun julo Lyrics
  • Hymn 523 Awa ti gbe o sin Lyrics
  • Hymn 532 Oluwa, ’Wo ki o so gba Lyrics
  • Hymn 340 Jesu Oluwa, Oba mi Lyrics
  • Hymn 78 Onigbagbo, e bu s’ ayo Lyrics
  • Hymn 265 ‘Gbani t’ Olorun sokale Lyrics
  • Hymn 536 Jesu, nib’ eni Re pade Lyrics
  • Hymn 44 A f’ope f’ Olorun Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version