Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics

Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 426 Jesu, ba Ijo Re gbe Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Jesu, ba Ijo Re gbe,
Samona at’ odi re,
B’o ti nla ’danwo koja;
Awa mbe O, gbo tiwa.

2 F’ owo ife Re yi ka,
Dabobo lowo ota,
Tu ninu nigba ibi;
Awa mbe O, gbo tiwa.

3 M’ eko at’ iwa re mo;
Je k’o fi suru duro;
K’o simi le ’leri Re;
Awa mbe O, gbo tiwa.

4 Pelu re lojo gbogbo,
K’o bo lowo isina;
K’o ma sise fun yin Re;
Awa mbe O, gbo tiwa.

5 K’ ohun re ma ja goro,
N’ ikilo ’dajo ti mbo;
Ni siso ife Jesu:
Awa mbe O, gbo tiwa.

6 Wa tun ibaje re se,
Wa tun Tempili Re ko,
Fi ara Re han nibe,
Awa mbe O, gbo tiwa.

7 Wad a gbogbo ide re
Mu ’lara at’ ija tan,
M’ alafia orun wa,
Awa mbe O, gbo tiwa.

8 Mu gbogbo oran re to;
Ma je k’owo Esu te;
Ki aiye ma le tan je:
Awa mbe O, gbo tiwa.

9 K’ eko re je okanna,
N’nu otito at’ ife;
K’o fa opo s’ igbagbo
Awa mbe O, gbo tiwa.

10 K’o ma toju alaini,
K’o si ma wa asako,
At’ onirobinuje:
Awa mbe O, gbo tiwa.

11 Ma je k’ife re tutu,
M’ awon oluso gboiya,
S’ agbara y’ agbo Re ka:
Awa mbe O, gbo tiwa.

12 K’ awon alufa ma bo;
Kin won j’ oluso toto,
Lati ma to Ijo Re.
Awa mbe O, gbo tiwa.

13 Ki nwon se bi nwon ti nso,
K’ nwon f’apere mimo han
Bi asaju agbo Re,
Awa mbe O, gbo tiwa.

14 F’ or’- ofe Enit’ o ku
At’ ife Baba ba gbe;
K’ Emi ma samona re:
Awa mbe O, gbo tiwa.

15 We gbogbo arun re nu;
L’ eru on ’yemeji lo,
Mu ’segun re de Kankan.
Awa mbe O, gbo tiwa.

16 Ran lowo nigba awe,
Tit’ ise re o pari,
T’ Oko- yawo y’o si de:
Awa mbe O, gbo tiwa.

17 Nigbana k’O se logo,
Ati ni ailabawon,
L’ewa didan t’o ye O.
Awa mbe O, gbo tiwa.

18 Mu ye, ki on ba le pin
N’nu aye t’ Iwo npese;
Lai, k’o n’ ibukun nibe.
Awa mbe O, gbo tiwa.

Post navigation

Previous: Hymn 425 E wa k’ a da orin wa po Lyrics
Next: Hymn 427 Oluwa orun on aiye Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 465 Jesu fe mi, mo mo be Lyrics
  • Hymn 481 Gba Jesu f’ ite Re sile Lyrics
  • Hymn 73 Ojo dajo, ojo eru! Lyrics
  • Hymn 520 Awon mimo, lala pari Lyrics
  • Hymn 544 Wa, iwo Isun ibukun Lyrics
  • Hymn 184 Jesu, l’ara Re l’awa nwo Lyrics
  • Hymn 83 Ayo b’ aiye ! Oluwa de Lyrics
  • Hymn 25 Ojo ‘simi at’ ayo Lyrics
  • Hymn 401 Aye si mbe! ile Odagutan Lyrics
  • Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics
  • Hymn 404 Nigbat’ idanwo yi mi ka Lyrics
  • Hymn 177 Jesu, emi o fi okan mi fun O Lyrics
  • Hymn 217 L’ owuro Ojo Ajinde Lyrics
  • Hymn 181 Olorun ’yanu ! ona kan Lyrics
  • Hymn 501 Ji, okan mi, dide giri Lyrics
  • Hymn 594 E tun won ko fun mi ki ngbo Lyrics
  • Hymn 556 Fun anu to po b’iyanrin Lyrics
  • Hymn 123 Baba orun ! emi fe wa Lyrics
  • Hymn 441 Tal’ awa ba ha to lo Lyrics
  • Hymn 476 Awon kekeke wo l’ eyi Lyrics
  • Hymn 541 Lekan k’a to tuka Lyrics
  • Hymn 362 Larin ewu at’ osi Lyrics
  • Hymn 295 Baba orun, nin’ oro Re Lyrics
  • Hymn 10 Baba mi gbo temi Lyrics
  • Hymn 366 Olusagutan y’o pese Lyrics
  • Hymn 510 Isimi wa l’orun, ko si l’aiye yi Lyrics
  • Hymn 258 Lehin aiye okunkun yi Lyrics
  • Hymn 382 Iranse Oluwa Lyrics
  • Hymn 105 ’Wo Omo ayanfe Baba Lyrics
  • Hymn 352 Ewa ’tanna oro kutu Lyrics
  • Hymn 206 Wakati didun ni fun mi Lyrics
  • Hymn 180 Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin Lyrics
  • Hymn 546 Si ohun ti a gbin Lyrics
  • Hymn 158 Olorun, fi opa Re Lyrics
  • Hymn 285 Iyin ainipekun Lyrics
  • Hymn 378 Omogun Krist, dide Lyrics
  • Hymn 31 Bi mo ti yo, lati gb’ oro Lyrics
  • Hymn 144 Okan mi, sunmo ’te anu Lyrics
  • Hymn 473 Mo fe gbo itan kanna Lyrics
  • Hymn 460 Bi osun gbege eti ’do Lyrics
  • Hymn 322 Mo gbohun Jesu t’ o wipe Lyrics
  • Hymn 530 Oluwa, mo de ’bi ’te Re Lyrics
  • Hymn 547 Olorun, a so oro Re Lyrics
  • Hymn 196 Hosanna s’Omo Dafidi Lyrics
  • Hymn 600 Olorun, d’ Oba si Lyrics
  • Hymn 90 Apata aiyeraiye Lyrics
  • Hymn 317 Ohun ogo Re l’ a nrohin Lyrics
  • Hymn 568 Okan mi, yin Oba orun Lyrics
  • Hymn 266 Emi Olorun mi Lyrics
  • Hymn 380 Baba mi, ‘gba mba / nsako lo Lyrics
  • Hymn 391 Gb’ agbelebu re, ni Krist wi Lyrics
  • Hymn 140 Jesu y’o joba ni gbogbo Lyrics
  • Hymn 23 Oluwa, ojo t’ o fun wa pin Lyrics
  • Hymn 335 Jesu Oluwa, a fe O Lyrics
  • Hymn 62 Sunm’ odo wa, Emmanuel Lyrics
  • Hymn 313 Igbagbo mi wo O Lyrics
  • Hymn 407 Emi okan wa npe Lyrics
  • Hymn 142 Kristi sun f’ elese Lyrics
  • Hymn 523 Awa ti gbe o sin Lyrics
  • Hymn 45 Wa, enyin olope, wa Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version