Skip to content

info@example.com

Treasure Hymns – Yoruba

  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
  • About
  • Contact
  • Home
  • Privacy Policy
  • Sample Page
  • Terms and Conditions
  • Terms of Service
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics

  1. Home   »  
  2. Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics

Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics

December 17, 2025December 17, 2025 treasurehymnsYouruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

Hymn 279 Emi ’bukun ti a nsin Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Emi ’bukun ti a nsin
Pelu Baba at’ Oro,
Olorun aiyeraiye;
Emi Mimo, gbo ti wa.

2 Emi Mimo, ’Daba orun,
Iri tin se lat’ oke,
Emi ’ye at’ ina ’fe;
Emi Mimo, gbo ti wa.

3 Isun ipa at’ imo,
Ogbon at’ iwa- mimo,
Oye, imoran, eru;
Emi Mimo, gbo ti wa.

4 Isun ife, Alafia,
Suru, ibisi ’gbagbo,
’Reti, ayo ti ki tan;
Emi Mimo, gbo ti wa.

5 Emi Afonahan ni,
Emi tin mu ’mole wa,
Emi agbara gbogbo;
Emi Mimo, gbo ti wa.

6 ’Wo t’ o mu Wundia bi,
Eni t’ orun t’ aiye mbo,
T’a ran lati tun wa bi;
Emi Mimo, gbo ti wa.

7 ’Wo ti Jesu t’ oke ran
Wa tu enia Re ninu,
Kin won ma ba nikan wa;
Emi Mimo, gbo ti wa.

8 ’Wo t’O nf’ ore kun Ijo,
T’O nfi ife Baba han,
T’O nmu k’o ma ri Jesu;
Emi Mimo, gbo ti wa.

9 Iwo ti nf’ onje iye,
At’ otito na bo wa,
Ani, On t’O ku fun wa;
Emi Mimo, gbo ti wa.

10 F’ ebun meje Re fun ni,
Ogbon, lati m’ Olorun,
Ipa lati ko ota;
Emi Mimo, gbo ti wa.

11 Pa ese run lokan wa,
To ife wa si ona,
B’a ban se O, mu suru;
Emi Mimo, gbo ti wa.

12 Gbe wa dide, b’a subu,
Ati nigba idanwo,
Sa pe wa pada pele;
Emi Mimo, gbo ti wa.

13 Wa, k’O mu ailera le,
F’ igboya fun alare,
Ko wa l’ oror t’a o so;
Emi Mimo, gbo ti wa.

14 Wa ran okan wa lowo,
Lati mo otito Re,
Ki ’fe wa le ma gbona;
Emi Mimo, gbo ti wa.

15 Pa wa mo l’ona toro
Baw a wi nigb’a nsako,
Ba wa bebe l’ adura,
Emi Mimo, gbo ti wa.

16 Eni Mimo, Olufe,
Wa gbe inu okan wa;
Ma fi wa sile titi:
Emi Mimo, gbo ti wa. Amin.

Post navigation

Previous: Hymn 278 Si O, Olutunu orun Lyrics
Next: Hymn 280 Mimo, mimo, mimo! Olodumare! Lyrics

Leave a Reply Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Hymns You May Like

  • Hymn 363 Olorun emi wa, at’ igbala wa Lyrics
  • Hymn 326 Ona ara l’Olorun wa Lyrics
  • Hymn 430 Mo nlo; talaka Mi mbe lodo nyin Lyrics
  • Hymn 197 W’ Olori Alufa Giga Lyrics
  • Hymn 442 Oluwa, mo mba O pade nihin Lyrics
  • Hymn 209 Ife lo to bayi Lyrics
  • Hymn 294 Iwe kan wa ti kika re Lyrics
  • Hymn 87 Wa enyin oloto Lyrics
  • Hymn 4 Oluwa mi, mo njade lo Lyrics
  • Hymn 447 Duro, omo ogun Lyrics
  • Hymn 403 Eredi irokeke yi Lyrics
  • Hymn 510 Isimi wa l’orun, ko si l’aiye yi Lyrics
  • Hymn 340 Jesu Oluwa, Oba mi Lyrics
  • Hymn 469 Orun tanmole Lyrics
  • Hymn 531 Oluwa, a wa ’do Re Lyrics
  • Hymn 278 Si O, Olutunu orun Lyrics
  • Hymn 409 Loni ni Jesu pe Lyrics
  • Hymn 521 Odun nyipo, o nji emi Lyrics
  • Hymn 597 Iyin, ola, ogo, ’bukun Lyrics
  • Hymn 30 Jesu, a fe pade Lyrics
  • Hymn 169 Apata aiyeraiye Lyrics
  • Hymn 376 A ko ni ’bugbe kan nihin Lyrics
  • Hymn 471 Olorun ite ogo Re Lyrics
  • Hymn 345 Ara, e je k’ a jumo rin Lyrics
  • Hymn 509 O s’ ohun t’o ti mi loju Lyrics
  • Hymn 244 Olorun goke lo Lyrics
  • Hymn 405 Tire l’ola Baba Lyrics
  • Hymn 284 E fi ogo fun Baba Lyrics
  • Hymn 72 Onidajo mbo wa Lyrics
  • Hymn 297 Tori Mi at’ Ihinrere Lyrics
  • Hymn 118 Lat’ oke tutu Grinland Lyrics
  • Hymn 31 Bi mo ti yo, lati gb’ oro Lyrics
  • Hymn 188 Olorun, Baba mi, ’Wo npe Lyrics
  • Hymn 558 Wo, owon Olurapada Lyrics
  • Hymn 370 Emi ‘ba le f’ iwa pele Lyrics
  • Hymn 528 Gbogbo enyin ti ngbe aiye Lyrics
  • Hymn 598 E korin s’Olorun wa Lyrics
  • Hymn 242 Alafia f’ ojo na, Alleluya Lyrics
  • Hymn 252 Olor’ Alufa giga kan Lyrics
  • Hymn 54 Gbo ohun olore Lyrics
  • Hymn 325 Om’ Olorun a ko ri O Lyrics
  • Hymn 526 Isin Jesu ni ’funni Lyrics
  • Hymn 57 Wo oju sanma ohun ni Lyrics
  • Hymn 459 Ojo oni lo tan Lyrics
  • Hymn 204 Wo Odagutan ti o ru Lyrics
  • Hymn 120 Oluwa y’o tip e to Lyrics
  • Hymn 183 Gbogbo eje eran Lyrics
  • Hymn 134 Lati erekusu Lyrics
  • Hymn 116 Ji, apa Olorun, k’ o ji Lyrics
  • Hymn 532 Oluwa, ’Wo ki o so gba Lyrics
  • Hymn 332 Olugbala mi, ife Re Lyrics
  • Hymn 487 Ile- eko ojo ’simi Lyrics
  • Hymn 514 Gbat’ a kun fun banuje Lyrics
  • Hymn 585 Jesu, o ha le je be pe Lyrics
  • Hymn 464 Mo fe ki ndabi Jesu Lyrics
  • Hymn 395 Ko mi Oluwa, bi a ti Lyrics
  • Hymn 180 Mo f’ igbagbo b’ Olorun rin Lyrics
  • Hymn 353 Jesu, mo gb’ agbelebu mi Lyrics
  • Hymn 175 Otosi elese, e wa Lyrics
  • Hymn 456 Jesu, Baba omode Lyrics

Archives

  • December 2025

Categories

  • Uncategorized
  • Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
Proudly powered by WordPress | Theme: goldy-mex by inverstheme.
Go to mobile version