Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 8 Imole oro, didun yi Lyrics

Hymn 8 Imole oro, didun yi Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Imole oro, didun yi
Ji mi nin’ orun mi;
Baba, ife Tire nikan
L’ o pa omo Re mo.

2 Ni gbogbo oni, mo be O,
Ma se Oluso mi;
Dariji mi, Jesu mimo
Ki’ m je Tire loni.

3 Wa se ’bugbe Re ninu mi,
Emi ore- ofe!
So mi di mimo laiye yi,
K’ emi le r’ oju Re. Amin.

Exit mobile version