Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 68 Oluwa ni Oba Lyrics

Hymn 68 Oluwa ni Oba Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Oluwa ni Oba;
E bo Oluwa nyin:
Eni kiku, sope,
Y’ ayo ’segun titi
Gb’ okan at’ ohun nyin soke
“Eyo,” mo sit un wi, “Eyo.”

2 Olugbala Joba,
Olorun otito;
’Gbat’ o we se wa nu,
O goke lo joko;
Gb’ okan at’ ohun, &c;

3 O mbe lodo Baba,
Titi gbogbo ota,
Yio teri won ba,
Nipa ase Tire.
Gb’ okan at’ ohun, &c;

4 Yo n’ ireti ogo
Onidajo mbo wa;
Lati mu ’ranse Re
Lo ’le aiyeraiye.
Afe gbohun Angel nla na,
Ipe y’o dun wipe, “E yo,”. Amin

Exit mobile version