Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 67 Jesu kigbe pe, “Emi de Lyrics

Hymn 67 Jesu kigbe pe, “Emi de Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Jesu kigbe pe, “Emi de,
T’ emi ti ife nla”
Okan mi dahun pe, “Ma bo,”
K’ o mu igbala wa.

2 Wa, gba oran Baba Re ro;
Si mu ogo Re ran;
Wa, ji oku iranse Re,
K’ o si so won d’ otun.

3 Ma bo wa ’larin ogun Re
Lati gb’oruko won;
K’ o si m’ ajo kikun pada
Lati y’ ite Re ka.

4 Olurapada, wa Kankan,
Mu ojo nla ni wa.
Wa, k’ okan wa ma ba daku,
Nitori pipe Re. Amin.

Exit mobile version