Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 600 Olorun, d’ Oba si Lyrics

Hymn 600 Olorun, d’ Oba si Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Olorun, d’ Oba si,
K’Oba k’o pe titi,
Da Oba si.
Jo, fun ni isegun,
Irora at’ ogo,
K’ o job ape titi,
Da Oba si.

2 Dide, Olorun wa,
T’ awon ota re ka,
Bi won subu.
Mu idamu ba won,
Fo ’gba rikisi won,
Iwo l’ a gbekele,
Jare gba wa.

3 Fi ebun rere Re
Te Oba wa lorun,
K’o pe titi.
K’o duro ti ofin,
K’ a le ma f’ ayo wi
Lati okan wa pe,
Da Oba si. Amin.

Exit mobile version