Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 59 Wa iwo Jesu t’ a nreti Lyrics

Hymn 59 Wa iwo Jesu t’ a nreti Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Wa iwo Jesu t’ a nreti
T’ a bi lati da ni n’ de,
Gba wa low’ eru at’ ese
Je k’ a ri isimi re:

2 Iwo ni itunu Israel,
Ireti Onigbagbo;
Ife gbogb’ orile- ede
Ayo okan ti nwona.

3 ’Wo t’ a bi lati gba wa la,
Omo ti a bi l’ Oba;
Ti a bi lati job alai,
Je ki ijoba Re de:

4 Fi Emi Mimo Re nikan,
Se akoso aiya wa;
Nipa itoye kikun Re
Gbe wa s’ ori ite Re. Amin.

Exit mobile version