Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 574 Oro alafia Lyrics

Hymn 574 Oro alafia Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Oro alafia,
La fi sin nyin, ara,
K’ alafia bi odo nla,
Ma ba nyin lo.

2 N’nu oro adura,
A f’ awon ara wa
Le iso Oluwa lowo,
Ore toto.

3 Oro ife didun,
L’a p’ odigbose;
Ife wa ati t’ Olorun,
Y’o ba won gbe.

4 Oro gbagbo lile,
Ni igbekele wa;
Pe Oluwa y’o se ranwo,
Nigba gbogbo.

5 Odigbose, ara,
N’ ife at’ igbagbo;
Tit’ ao fi tun pade loke,
N’ ile wa orun. Amin.

Exit mobile version