Hymn 564 L’oko Jesu, gbogbo ekun yio wole Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 L’oko Jesu, gbogbo ekun yio wole,
Ahon yio jewo Re pe On l’Oba ogo;
Ife Bab nip e, k’a pe l’ Oluwa,
Enit’ ise Oro lat’ aiyeraye.
2 Nipa Oro re l’a da ohun gbogbo,
Awon angeli at’ awon imole,
Ite, ijoba, at’ awoon irawo,
Gbogbo eda orun ninu ogun won.
3 O re ‘ra Re sile, alti gb’ oruko,
Lodo awon elese t’o wa kun fun;
Ko je ki egan ba le oruko yi,
Titi O fi jjinde t’a si se l’ogo.
4 Oruko yi lo f’ayo gbe lo s’orun,
Koja gbogboe eda lo sibi giga,
S’ite Olorun, s’okan aiya Baba,
O si fi ogo isimi pipe kun.
5 F’ ife daruko Re, enyin ara, wa
Pelu eru jeeje ati iyanu,
Olorun Oluwa, Krist, Olugbala
Titi lao ma sin O, ao ma teriba.
6 E je ki Jesu joba n’nu okan nyin’
Y’o mu ohun buburu gbogbo kuro;
We l’ ogagun nyin l’a koko idanwo;
E je ki ‘fe Re je odi yi nyin ka.
7 Arakunrin, Jesu yi yio tun pada,
N’nu ogo Bab, pel’ awon angeli;
Gbogbo orile ede y’o wari fun,
Okan wa y’o jewo pe, On ni Oba. Amin.
