Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 562 A korin s’ Omo Olorun Lyrics

Hymn 562 A korin s’ Omo Olorun Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 A korin s’ Omo Olorun,
Odagutan t’a pa;
Ti orun ati aiye mbo,
T’O ye lati joba.

2 Si O l’ awon Angeli nke,
L’ ekun gbogbo orun:
“Mimo, mimo, mim’ Olorun,
T’ ogo, at’ om’ ogun.”

3 Ijo Re li aiye dapo,
Lati ma kepe O;
Didan Olanla Olorun,
T’ O l’ agbara gbogbo.

4 Larin won ni gbogbo wa nfe
Lati yin eje Re;
Joba l’ aiye ati l’ orun,
’Wo Omo Olorun. Amin.

Exit mobile version