Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 558 Wo, owon Olurapada Lyrics

Hymn 558 Wo, owon Olurapada Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 ’Wo, owon Olurapada,
A fe ma gburo Re;
Ko s’ orin bi oruko Re,
T’o le dun t’ abo re.

2 A! a ba le ma gbohun Re!
L’ anu soro si wa;
Nin’ Alufa wa l’a o yo,
Melkisedek giga.

3 Jesu ni y’o se orin wa,
Nigbat’ a wa l’aiye;
A o korin ife Jesu,
’Gba nkan gbogbo baje.

4 Nigba ’ba yo soke lohun,
Pelu ’jo, eni Re;
’Gbana a o korin kikan,
Krist ni y’o j’ orin wa. Amin.

Exit mobile version