Hymn 525 Ara, iwo si| waju wa lo Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 Ara, iwo si| waju wa lo,
Emi re mi| mo si ti fo lo,
Sibiti ko ni | s’ ekun mo;
Ti | ko si irora.
2 O bo lowo| eru ara
Ati lowo| aniyan aiye:
Nib’ eni- buburu| ye yonu,
Ti a| lare si simi.
3 ’Wo ti rin ajo| aiye ja,
O ti| gb’ agbelebu re;
Krist ti fie se re| le ona,
Lati| de ib’ isimi.
4 Bi Lasaru| l’o si sun,
L’ a| kaiya Baba re,
Nib ’eni- buburu| ye yonu,
Ti a| lare si simi.
5 Ese ko le | ba o je mo,
I| yemeji d’ opin;
Igbagbo re ni| nu Kristi
At’ Emi| ko ni ye mo lai.
6 L’ orun lohun| n’ iwo o ba
Awon ore| t’o ti lo saju;
Nib’ eni- buburu | ye yonu,
Ti a| lare si simi.
7 Alufa ti wi ni| sisiyi pe,
Eru f’eru, e| rupe f’erupe;
Awa si ko e| rupe bo o,
A si | sami s’ori re.
8 Sugbon emi re| ti fo lo,
So| do awon mimo;
Nib’ eni- buburu| ye yonu,
Ti a| lare si simi.
9 ’Gbat’ Olu| wa ba sip e
A| wa t’o ku lehin;
Oluwa wa, | awa be O,
K’ai| ye ma ba wa je,
10 K’ olukuluku wa, b’ a| ra yi,
Le ri| aye lodo Re,
Nib’ eni- buburu | ye yonu,
Ti a| lare si simi. Amin.