Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 509 O s’ ohun t’o ti mi loju Lyrics

Hymn 509 O s’ ohun t’o ti mi loju Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 O s’ ohun t’o ti mi loju,
Pe, nigba kan l’aiye mi,
Olugbala nkanu lasan,
O npe mi, mo si ndahun pe,
“T’ emi sa, nko nani Re.”

2 Sugbon O ri mi; mo si wo
L’ or igi agbelebu;
Mo si gbo, “Fiji won Baba,”
Okan mi f’ inira wipe,
Em’ o nani Re die.”

3 Lojojumo li anu Re
Nse ’wosan fun okan mi,
Agbara at’ ife l’ O fi
Nfa mi mora, mo si wipe,
“Ngo nani Re die si.”

4 Ife Re ga ju orun lo,
O si jin ju okun lo;
Ife Re na l’ o segun mi,
Je kin le wi nitoto pe,
“Em’ o wa fun O titi.” Amin.

Exit mobile version