Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 50 Ojo ’dajo on ’binu Lyrics

Hymn 50 Ojo ’dajo on ’binu Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Ojo ’dajo on ’binu,
Ojo ti Jesu pa ni,
Gongo a so n’ ijo na !

2 Kikan n’ ipe o ma dun,
Isa oku yio si,
Gbogbo oku y’o dide.

3 Iku papa y’o diji,
Eda gbogbo y’o dide
Lati j’ ipe Olorun.

4 A o si Iwe sile,
A o si ka ninu re
Fun ’dajo t’oku t’aye.

5 Onidajo Ododo,
Jo w’ ese mi gbogbo nu
K’ ojo ’siro na to de. Amin.

Exit mobile version