Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 493 Hosanna! e korin soke Lyrics

Hymn 493 Hosanna! e korin soke Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Hosanna! e korin soke,
S’ omo nla Dafidi;
Pelu Kerub ati Seraf
K’a yin Om’ Olorun.

2 Hosanna! eyi na nikan,
L’ ahon wa le ma ko;
Iwo ki o kegan ewe,
Ti nkorin iyin Re.

3 Hosanna! Alufa, Oba,
Ebun Re tip o to!
Eje Re l’ o je iye wa,
Oro Re ni onje.

4 Hosanna! Baba, awa mu
Ore wa wa fun O,
Ki se wura on ojia,
Bikose okan wa.

5 Hosanna! Jesu, lekan ri,
O yin awon ewe;
Sanu fun wa, si f’ eti si
Orin awa ewe.

6 Jesu, b’ o ba ra wa pada,
T’ a si wo joba Re;
A o fi harpu wura ko
Hosanna titi lai. Amin.

Exit mobile version