Hymn 486 Oj’ oni lo Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 Oj’ oni lo,
Jesu Baba,
Boju Re w’ emi omo Re.
2 ’Wo Imole,
Se ’toju mi;
Tan imole Re yi mi ka.
3 Olugbala,
Nko ni beru,
Nitori O wa lodo mi.
4 Nigba gbogbo
Ni oju Re
Nso mi, gbat’ enikan ko si.
5 Nigba gbogbo
Ni eti Re
Nso mi, gbat’ enikan ko si.
6 Nigba gbogbo
Ni eti Re
Nsi si adura omode.
7 Nitorina
Laisi foya,
Mo sun, mo si simi le O.
8 Baba, Omo,
Emi Mimo
Ni iyin ye l’ orun l’ aiye. Amin.
