Hymn 484 Wa, ba wa jeun, Oluwa Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
I. Wa, ba wa jeun, Oluwa,
Je k’ a ma yin oruko Re;
Wa busi onje wa; si je
K’ a le ba O jeun l’ orun. Amin.
II. A f’ ope fun O, Oluwa,
Fun onje wa, at’ ebun mi;
Fi onje orun b’ okan wa,
Onje iye lat’ oke wa. Amin.