Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 477 Odagutan, ’Wo ti re Lyrics

Hymn 477 Odagutan, ’Wo ti re Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Odagutan, ’Wo ti re
Omo Re kekere l’ ekun:
Wo b’ o ti dubule je
Layo ninu iboji Re:
Ko s’ ami irora mo,
T’ o nyo okan Re lenu.

2 ’Wo ko mu pe titi mo
L’ aiye ekun on osi yi;
Iwo si f’ ayo gba a
Si ile orun mimo ni;
O woso ala mimo,
O mba O gbe n’ imole.

3 L’ aipetiti, Oluwa
Mu wa de ’bit’ omo yi lo;
Mu wa r’ ile ayo na,
T’ o nf’ onje orun bo won:
B’ O ti gb’ ayo wa lo yi,
’Gbana ao tun jere re. Amin .

Exit mobile version