Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 465 Jesu fe mi, mo mo be Lyrics

Hymn 465 Jesu fe mi, mo mo be Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Jesu fe mi, mo mo be,
Bibeli l’o so fun mi;
Tire l’ awon omode,
Nwon ko lagbara, On ni.

2 Jesu fe mi, En’ t’o ku
Lati si orun sile;
Yio we ese mi nu:
Jeki omo Re wole.

3 Jesu fe mi sibe si,
Bi emi tile s’aisan
Lor’ akete aisan mi,
Yio t’ ite Re wa so mi.

4 Jesu fe mi, y’o duro
Ti mi ni gbogb’ ona mi,
’Gba mba f’aiye yi sile,
Y’o mu mi re ’le orun. Amin.

Exit mobile version