Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 440 ‘Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re Lyrics

Hymn 440 ‘Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 ‘Wo Oba anu, lat’ or’ ite Re,
Fi ife wow a, si gbo igbe wa.

2 ‘Wo Olusagutan enia Re,
Pa awon abgo agutan Re mo.

3 Olugbala, iku Re n’iye wa,
F’iye anipekun fun gbogbo wa.

4 Onje orun, Iwo ni onje wa,
Se ‘ranwo okan wa nigba ‘ponju.

5 ‘Wo l’Alabaro, Ore elese,
‘Wo n’ Ibu ayo wa titi lailai.

6 Wa f’ore- ofe Re mu ‘nu wa dun,
Si je k’a ma ri ojurere Re.

7 Nigba osan, ati nigba oru,
Sunmo wa, k’o s’okun wa d’ imole.

8 Ma ba wa lo, k’o si ma ba wag be,
N’iye, n’iku, ma je itunu wa.

9 L’ojojumo f’oju ‘fe Re to wa,
Si mu wa de ‘le wa l’alafia. Amin.

Exit mobile version