Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 436 Ojo Ko; ase na leyi Lyrics

Hymn 436 Ojo Ko; ase na leyi Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Ojo Ko; ase na leyi;
Mo f’ara mi fun nyin;
E wo, mo f’ eje mi fun nyin,
Lati ran nyin pada.

2 O di ‘nu ‘joba Baba mi,
Ki mto tun ban yin mu;
‘Gbana ekun ko ni si mo,
A o ma yo titi.

3 Titi l’a o ma je onje eyi
K’ o to di igba na;
Ka gbogb’ aiye l’ opolopo
Y’o ma je, y’o ma mu.

4 ‘Bukun atorunwa y’o ma
Wa lor’ awon t’ o nje;
Ngo gbe or’ ite Baba mi
Ma pes’ aye fun won.

5 Sugbon nisisiyi, ago
Kikoro l’ em’ o mu,
Emi o mu nitori nyin,
Ago rora iku.

6 E ko le mo banuje mi,
E ko ti r’ogo mi;
Sugbon e ma s’eyi titi,
K’e ma fir anti mi. Amin.

Exit mobile version