Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 432 Gege bi oro ore Re Lyrics

Hymn 432 Gege bi oro ore Re Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Gege bi oro ore Re,
Ninu irele nla,
Emi o se yi Olua,
Emi o ranti Re.

2 Ara Re ti a bu fun mi,
Yio je onje mi;
Mo gba ago majemu Re,
Lati se ranti Re.

3 Mo le gbagbe Getsemane,
Ti mo r’ ijamu Re,
Iya on ogun eje Re,
Ki nma sir anti Re?

4 Ngo ranti gbogbo ‘rora Re,
At’ ife Re si mi;
Bi o ku emi kan fun mi,
Emi o ranti Re.

5 ‘Gbati enu mi ba pamo,
Ti iye mi bar a,
Ti O ba de n’ ijoba Re.
Jesu, jo ranti mi. Amin.

Exit mobile version