Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 414 F’ awon enia Re Lyrics

Hymn 414 F’ awon enia Re Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 F’ awon enia Re,
T’ o ti f’ aiye sile;
Awon t’ o mo O, t’ o sin O,
Gba orin iyin wa.

2 F’ awon enia Re,
Gba ohun ope wa;
Awon t’ o fi O s’ esan won,
Nwon ku n’ igbagbo Re.

3 Ni gbogbo aiye won,
’Wo ni nwon nwo l’oju:
Emi Mimo Re l’o nko won,
Lati s’ ohun gbogbo.

4 Fun eyi, Oluwa,
A nyin oruko Re;
Je k’ a ma tele iwa won,
Ki a le ku bi won. Amin.

Exit mobile version