Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 412 Mura, elese, lati gbon Lyrics

Hymn 412 Mura, elese, lati gbon Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Mura, elese, lati gbon,
Ma duro de ojo ola;
Niwon b’ o ti kegan ogbon,
Be l’ o si soro lati ri.

2 Mura lati bere anu,
Ma duro de ojo ola;
Ki igba re ko ma ba tan,
Ki ojo ale yi to tan.

3 Mura, elese, k’ o pada,
Ma duro de ojo ola;
Nitori k’ egun ma ba o,
K’ ojo ola k’ o to bere.

4 Mura lati gba ibukun,
Ma duro de ojo ola;
Ki fitila re ma ba ku,
K’ ise rere re to bere.

5 Oluwa, y’elese pada,
Ji kuro ninu were re;
Ma je k’o tapa s’imo Re,
K’o ma f’ egbe re se ’lora. Amin.

Exit mobile version