Hymn 406 Enyin t’ ongbe ngbe, e wa mu Lyrics
Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook
1 Enyin t’ ongbe ngbe, e wa mu
Omi iye ti nsan;
Lati orison ti Jesu,
Laisanwo l’ awa nbu.
2 Wo! b’ o tip e to t’ e tin mu
Ninu kanga eke,
T’ e nl’ agbara at’ ogun nyin
Ninu nkan t’ o nsegbe.
3 Jesu wipe, isura mi
Ko lopin titi lai;
Yio f’ ilera lailai fun
Awon t’ o gbo Tire. Amin.
