Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 398 Emi at’ ara ile mi Lyrics

Hymn 398 Emi at’ ara ile mi Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Emi at’ ara ile mi,
Yio ma sin Oluwa wa;
Sugbon emi papa;
Yio f’ iwa at’ oro han,
Pe mo mo Oluwa t’ orun,
Mo nfokan toto sin.

2 Em’ o f’ apere ’re le ’le;
Ngo mu idena na kuro;
Lodo om’ odo mi;
Ngo f’ ise won han n’ iwa mi,
Sibe n’nu ’se mi ki nsi ni
Ola na ti ife.

3 Emi ki y’o soro gb’ ipe,
Emi ki y’o pe tu ninu,
Om’ ehin Olorun;
Mo si fe je eni mimo,
Ki nsi fa gbogbo ile mi,
S’oju ona orun.

4 Jesu, b’O ba da ’na ’fe na,
Ohun elo t’ Iwo fe lo,
Gba s’ owo ara Re!
Sise ife rere n’nu mi,
Ki nfi b’ onigbagbo toto
Ti ngbe l’ aiye han won.

5 Fun mi l’ ore- ofe toto,
Nje! Emi de lati jeri
’Yanu oruko Re,
Ti o gba mi l’owo egbe;
Ire eyi t’a mo l’ okan,
Ti gbogb’ ahon le so.

6 Emi t’o bo lowo ese,
Mo wa lati gba ’le mi la,
Ki nwasu ’dariji;
F’omo, f’aya, f’ omo- do mi,
Lati mu won to ’na rere
Lo si orun mimo. Amin.

Exit mobile version