Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 347 Wo! b’ o ti dun to lati ri Lyrics

Hymn 347 Wo! b’ o ti dun to lati ri Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Wo! b’ o ti dun to lati ri
Awon ara t’ o re;
Ara ti okan won s’ okan,
L’ egbe ide mimo.

2 ’Gba isan ’fe t’ odo Krist sun,
O san s’ okan gbogbo;
Alafia Olodumare
Dabobo gbogbo re.

3 O dabi ororo didun,
Ni irugbon Aaron;
Kikan re m’ aso re run ’re,
O san s’ agbada re.

4 O dara b’ iri owuro,
T’ o nse soke Sion,
Nibi t’ Olorun f’ ogo han,
T’ o m’ ore- ofe han. Amin.

Exit mobile version