Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 343 Fe enikeji re Lyrics

Hymn 343 Fe enikeji re Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 “Fe enikeji re,”
Ase Oluwa ni;
O sa f’ ara Re s’ apere,
Ni fife t’ O fe wa.

2 “Fe enikeji re,”
N’ ire tabi n’ ija;
O ko w ape k’a f’ ota wa,
K’a f’ ore san ibi.

3 “Fe enikeji re,”
Oluwa nke tantan;
O ye ki gbogbo wa mura,
K’a f’ ore san ibi.

4 Fe enikeji re,
At’ aladugbo re,
Pelu gbogb’ eni yi o ka,
At’ ota re pelu.

5 K’ a f’ enikeji wa,
Bi Jesu ti fe wa,
Jesus a f’ awon ota Re,
O si sure fun won. Amin.

Exit mobile version