Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 314 Jesu, Olugbala, wo mi Lyrics

Hymn 314 Jesu, Olugbala, wo mi Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Jesu, Olugbala, wo mi,
Are mu mi, ara nni mi;
Mo de lati gb’ ara le O;
’Wo ’simi mi.

2 Bojuwo mi, o re mi tan;
Irin ajo na gun fun mi;
Mo nwa ’ranwo agbara Re,
’Wo Ipa mi.

3 Idamu ba mi l’ona mi,
Oru sokun, iji si nfe,
Tan imole si ona mi,
’Wo ’Mole mi.

4 Gba Satani ba tafa re,
’Wo ni mo nwo: nko beru mo;
Agbelebu Re l’abo mi,
’Wo Alafia mi.

5 Mo nikan wa leti Jordan,
Ninu ’waiya- ’ja jelo ni:
’Wo ki yio je k’emi ri;
’Wo Iye mi.

6 Gbogbo aini, ’Wo o fun mi
Titi d’opin; l’onakona;
Ni ’ye, ni ’ku, titi lailai,
’Wo Gbogbo mi. Amin.

Exit mobile version