Site icon Treasure Hymns – Yoruba

Hymn 299 Ninu gbogbo iji ti nja Lyrics

Hymn 299 Ninu gbogbo iji ti nja Lyrics

Youruba Iwe Orin Mimo Anglican Hymnbook

 

1 Ninu gbogbo iji ti nja,
Ninu gbogbo igbi ‘ponju,
Abo kan mbe, ti o daju;
O wa labe ite- anu.

2 Ibi kan wa ti Jesu nada
Ororo ayo s’ ori wa;
O dun ju ibi gbogbo lo;
Ite- anu t’ a f’eje won.

3 Ibi kan wa fun idapo,
Nibi ore npade ore;
Lairi ‘ra, nipa igbagbo,
Nwon y’ ite- anu kanna ka.

4 A! nibo ni a bas a si,
Nigba ‘danwo at’ iponju?
A ba se le bori Esu,
Bosepe ko si ‘te- anu?

5 A! bi idi l’a fo sibe,
B’enipe aiye ko si mo,
Orun wa ‘pade okan wa,
Ogo sib o ite- anu. Amin.

Exit mobile version